1 KỌ́RÍŃTÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1-3)
Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí àwọn ará Kọ́ríńtì (4-9)
Ó gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n wà níṣọ̀kan (10-17)
Kristi, agbára àti ọgbọ́n Ọlọ́run (18-25)
Ẹ máa yangàn nínú Jèhófà nìkan (26-31)
2
Iṣẹ́ ìwàásù Pọ́ọ̀lù ní Kọ́ríńtì (1-5)
Ọgbọ́n Ọlọ́run ju ti èèyàn lọ (6-10)
Ẹni tara àti ẹni tẹ̀mí (11-16)
3
Àwọn ará Kọ́ríńtì ṣì jẹ́ ẹni tara (1-4)
Ọlọ́run ń mú kó dàgbà (5-9)
Fi ohun tí kò lè jóná kọ́lé (10-15)
Ẹ̀yin ni tẹ́ńpìlì Ọlọ́run (16, 17)
Ọgbọ́n ayé jẹ́ òmùgọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run (18-23)
4
Ó yẹ kí ìríjú jẹ́ olóòótọ́ (1-5)
Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀ àwọn òjíṣẹ́ tó jẹ́ Kristẹni (6-13)
Pọ́ọ̀lù ń bójú tó àwọn tó jẹ́ ọmọ rẹ̀ nípa tẹ̀mí (14-21)
5
Ẹjọ́ ìṣekúṣe tó wáyé (1-5)
Ìwúkàrà díẹ̀ ló ń mú gbogbo ìṣùpọ̀ wú (6-8)
Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò (9-13)
6
Àwọn ará ń gbéra wọn lọ sílé ẹjọ́ (1-8)
Àwọn tí kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run (9-11)
Ẹ máa yin Ọlọ́run lógo nínú ara yín (12-20)
7
Ìmọ̀ràn fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn tó ti gbéyàwó (1-16)
Ẹ wà ní ipò tí ẹ wà nígbà tí a pè yín (17-24)
Àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó (25-40)
8
9
10
Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ látinú ìtàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (1-13)
Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ nípa ìbọ̀rìṣà (14-22)
Òmìnira àti gbígba tàwọn ẹlòmíì rò (23-33)
11
12
13
14
15
Àjíǹde Kristi (1-11)
Àjíǹde jẹ́ ìpìlẹ̀ ìgbàgbọ́ (12-19)
Àjíǹde Kristi jẹ́ àmì ìdánilójú (20-34)
Ara ìyára àti ara tẹ̀mí (35-49)
Àìkú àti àìdíbàjẹ́ (50-57)
Ẹ ní ohun púpọ̀ láti ṣe nínú iṣẹ́ Olúwa (58)
16
Wọ́n kó nǹkan jọ fún àwọn Kristẹni tó wà ní Jerúsálẹ́mù (1-4)
Ètò ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù (5-9)
Ó ṣètò bí Tímótì àti Àpólò ṣe máa bẹ àwọn ará wò (10-12)
Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni (13-24)