Lọ sí Ọ̀kan Lára Àwọn Àpéjọpọ̀ “Ọ̀nà Ìgbésí Ayé tí Ọlọ́run Fẹ́” Nítòsí Rẹ!
Ní Nàìjíríà, àpéjọpọ̀ ọlọ́jọ́ mẹ́ta ti Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà yìí yóò bẹ̀rẹ̀ ní October 16, yóò sì máa bá a lọ títí di ìbẹ̀rẹ̀ January. Ní Nàìjíríà nìkan, a ṣètò fún 108 àpéjọpọ̀—46 ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, àti 62 ní àwọn èdè mẹ́rìnlá mìíràn tí ó jẹ́ Abua, Èdè Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà, Ègùn, Edo, Ẹ́fíìkì, Gòkánà, Haúsá, Ìgbò, Ijaw, Ísókó, Khana, Tiv, Urhobo, àti Yorùbá.
Wá gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ agbéniró tí a gbé karí Bíbélì àti àwọn àṣefihàn gbígbéṣẹ́ náà. Tún wá gbádùn àwòkẹ́kọ̀ọ́ gbígbéṣẹ́ tí ìmúra rẹ̀ jẹ́ ti aláràbarà, tí a pe àkọlé rẹ̀ ní “Ẹ̀yin Ìdílé—Ẹ Sọ Kíka Bíbélì Lójoojúmọ́ Di Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Yín!” Ọ̀fẹ́ ni ìjókòó.
Àwọn Ọ̀gangan Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ọ̀NÀ ÌGBÉSÍ AYÉ TÍ ỌLỌ́RUN FẸ́” Ti 1998 sí 1999
OCTOBER 16-18, 1998
MGBOKO UMUORIA 1 (Ìgbò)
ÙBOGÒ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
OCTOBER 23-25, 1998
IGWURUTA ALI 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 2 (Ìgbò)
ÙBOGÒ 2 (Ísókó)
OCTOBER 30–NOVEMBER 1, 1998
BENIN CITY 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 1 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT AKAN (Ẹ́fíìkì)
JOS 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 3 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 1 (Yorùbá)
Ọ̀TÀ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 3 (Ísókó)
UYÓ 1 (Ẹ́fíìkì)
NOVEMBER 6-8, 1998
AGBOR 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌBÀDÀN 1 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
JOS 2 (Haúsá)
KÀDÚNÁ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÒKÌTÌPUPA 2 (Yorùbá)
Ọ̀TÀ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 4 (Ijaw)
ÙLÌ 1 (Ìgbò)
UYÓ 2 (Ẹ́fíìkì)
NOVEMBER 13-15, 1998
AGBOR 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 3 (Yorùbá)
ENUGU 1 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 1 (Ẹ́fíìkì)
KÀDÚNÁ 2 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 5 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 3 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 5 (Urhobo)
ÙLÌ 2 (Ìgbò)
UYÓ 3 (Ẹ́fíìkì)
NOVEMBER 20-22, 1998
AGBOR 3 (Esan)
ÀKÚRẸ́ 1 (Yorùbá)
BENIN CITY 4 (Edo)
DÁLÙWỌ́N 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ENUGU 2 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 3 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 5 (Gòkánà)
IKOT EKPENE 2 (Ẹ́fíìkì)
ÌLỌRIN 1 (Yorùbá)
KÀDÚNÁ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
KATSINA ALA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 6 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 6 (Urhobo)
ÙLÌ 3 (Ìgbò)
UYÓ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
NOVEMBER 27-29, 1998
AGBOR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 2 (Yorùbá)
BENIN CITY 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 1 (Ẹ́fíìkì)
DÁLÙWỌ́N 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ENUGU 3 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 6 (Abua)
IKOT EKPENE 3 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌLỌRIN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
KATSINA ALA 2 (Tiv)
MGBOKO UMUORIA 7 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 5 (Yorùbá) Y-4, 5, 7
ÙBOGÒ 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 4 (Ìgbò)
UYÓ 5 (Ẹ́fíìkì)
DECEMBER 4-6, 1998
AGBOR 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 3 (Yorùbá)
CALABAR 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
DÁLÙWỌ́N 6 (Yorùbá)
ENUGU 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 7 (Khana)
IKOT EKPENE 4 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 2 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 8 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 6 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 8 (Urhobo)
ÙLÌ 5 (Ìgbò)
UYÓ 6 (Ẹ́fíìkì)
DECEMBER 11-13, 1998
AGBOR 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
BADAGRY (Ègùn)
CALABAR 3 (Ẹ́fíìkì)
DÁLÙWỌ́N 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
ENUGU 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 8 (Ìgbò)
IKOT EKPENE 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ILÉṢÀ 3 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 9 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 7 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
ÙBOGÒ 9 (Urhobo)
ÙLÌ 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
UYÓ 7 (Ẹ́fíìkì)
JANUARY 8-10, 1999
CALABAR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 9 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 10 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 10 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 7 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Amẹ́ríkà)
UYÓ 8 (Gẹ̀ẹ́sì)