Lọ sí Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ìgbàgbọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” Nítòsí Rẹ!
Àpéjọpọ̀ ọlọ́jọ́ mẹ́ta ti Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà yí yóò bẹ̀rẹ̀ ní October 10, 1997, ní Nàìjíríà, a óò sì ṣe é títí di apá ìbẹ̀rẹ̀ January 1998. Ní Nàìjíríà, a ṣètò fún àpéjọ 109: 45 ní Gẹ̀ẹ́sì, 18 ní Yorùbá, àti 46 ní èdè 13 mìíràn—Àbúà, Èdè Àwọn Adití, Ẹdó, Ẹ́fíìkì, Ègùn, Haúsá, Ìgbò, Ijaw, Ishan, Ísókó, Ògònì, Tiv, àti Urhobo.
Má ṣe tàsé ọ̀pọ̀ àwíyé Bíbélì àti àwọn àṣefihàn gbígbéṣẹ́ tí ń súnni ṣiṣẹ́, tí a óò gbé jáde. Sì gbádùn àwòkẹ́kọ̀ọ́ ohun tí ń ṣẹlẹ̀ gidi nípa bí àwọn Kristẹni ṣe ń kojú àníyàn. Ọ̀fẹ́ ni gbogbo àkókò ìjókòó. Lọ sí èyíkéyìí nínú àwọn ọ̀gangan tí a tò sísàlẹ̀ wọ̀nyí.
Àwọn Ọ̀gangan Àpéjọpọ̀ Àgbègbè
MGBOKO UMUORIA 1 (Ìgbò)
October 17-19, 1997
MGBOKO UMUORIA 2 (Ìgbò)
October 24-26, 1997
MGBOKO UMUORIA 3 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 1 (Yorùbá)
October 31—November 2, 1997
ÌBÀDÀN 1 (Yorùbá)
IKOT AKAN (Ẹ́fíìkì)
ÌMÁLÀ 1 (Yorùbá)
JOS 1 (Haúsá)
KÀDÚNÁ 1 (Yorùbá)
KATSINA ALA 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 4 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 1 (Yorùbá)
Ọ̀TÀ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
OYÉDÉ 1 (Ísókó)
ÙBOGÒ 1 (Ijaw)
UYÓ 1 (Ẹ́fíìkì)
November 7-9, 1997
AGBOR 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
BADAGRY (Ègùn)
BENIN CITY 1 (Gẹ̀ẹ́sì)
ENÚGU 1 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 2 (Yorùbá)
JOS 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 1 (Ògònì)
ILÉṢÀ 1 (Yorùbá)
ÌMÁLÀ 2 (Yorùbá)
KÀDÚNÁ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
KATSINA ALA 2 (Tiv)
MGBOKO UMUORIA 5 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 2 (Yorùbá)
Ọ̀TÀ 3 (Yorùbá)
OYÉDÉ 2 (Ísókó)
ÙBOGÒ 2 (Urhobo)
ÙLÌ 1 (Ìgbò)
UYÓ 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
November 14-16, 1997
AGBOR 2 (Ishan)
BENIN CITY 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ENÚGU 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌBÀDÀN 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 2 (Àbúà)
IKOT EKPENE 1 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 2 (Yorùbá)
ÌMÁLÀ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
KÀDÚNÁ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 6 (Ìgbò)
ÒKÌTÌPUPA 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
OYÉDÉ 3 (Ísókó)
ÙBOGÒ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 2 (Ìgbò)
UYÓ 3 (Ẹ́fíìkì)
November 21-23, 1997
AGBOR 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
BENIN CITY 3 (Ẹdó)
CALABAR 1 (Ẹ́fíìkì)
ENÚGU 3 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 4 (Yorùbá)
IGWURUTA ALI 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 2 (Ẹ́fíìkì)
ILÉṢÀ 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌLỌRIN 1 (Yorùbá)
MGBOKO UMUORIA 7 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 5 (Yorùbá)
OYÉDÉ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 4 (Urhobo)
ÙLÌ 3 (Ìgbò)
UYÓ 4 (Ẹ́fíìkì)
November 28-30, 1997
AGBOR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 1 (Yorùbá)
BENIN CITY 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 2 (Ẹ́fíìkì)
ENÚGU 4 (Ìgbò)
ÌBÀDÀN 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 3 (Ẹ́fíìkì)
ÌLỌRIN 2 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 4 (Ìgbò)
UYÓ 5 (Ẹ́fíìkì)
December 5-7, 1997
AGBOR 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 2 (Yorùbá)
BENIN CITY 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
CALABAR 3 (Gẹ̀ẹ́sì)
ENÚGU 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÌBÀDÀN 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 5 (Ìgbò)
IKOT EKPENE 4 (Ẹ́fíìkì)
MGBOKO UMUORIA 9 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 7 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití)
ÙBOGÒ 6 (Urhobo)
ÙLÌ 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
UYÓ 6 (Ẹ́fíìkì)
December 12-14, 1997
AGBOR 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÀKÚRẸ́ 3 (Yorùbá)
CALABAR 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 6 (Gẹ̀ẹ́sì)
IKOT EKPENE 5 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 10 (Ìgbò)
Ọ̀TÀ 8 (Yorùbá)
ÙBOGÒ 7 (Urhobo)
ÙLÌ 6 (Ìgbò)
UYÓ 7 (Ẹ́fíìkì)
January 9-11, 1998
ÀKÚRẸ́ 4 (Gẹ̀ẹ́sì)
IGWURUTA ALI 7 (Gẹ̀ẹ́sì)
MGBOKO UMUORIA 11 (Gẹ̀ẹ́sì)
Ọ̀TÀ 9 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙBOGÒ 8 (Gẹ̀ẹ́sì)
ÙLÌ 7 (Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Àwọn Adití)
UYÓ 8 (Gẹ̀ẹ́sì)