Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 8, 2004
Oyún Ọ̀dọ́langba Ìṣòro Tó Kárí Ayé
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ àwọn ọmọbìnrin ló ń dojú kọ ìṣòro dídá tọ́jú ọmọ wọn jòjòló. Ǹjẹ́ wọ́n lè kẹ́sẹ járí báyìí? Ìrànlọ́wọ́ wo ló dára jù lọ tá a lè ṣe fáwọn ọ̀dọ́ kí wọ́n má bàa kó sínú ìṣòro yìí?
4 Oyún Ọ̀dọ́langba Ìṣòro Tó Kárí Ayé
8 Bí Àwọn Ọ̀dọ́langba Tó Di Ìyá Ọmọ Ṣe Lè Kojú Àwọn Ìṣòro Wọn
11 Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Ká sì Dáàbò Bò Wọ́n
13 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
14 Bí Èèyàn Rẹ Kan Bá Lárùn Ọpọlọ
17 Ohun Tó Sàn Ju Lílókìkí Nínú Ayé
24 Ilé Ìwé Jẹ́lé-Ó-Sinmi Tí Kò Ní Ohun Ìṣeré Ọmọdé
28 Àwọn Jagunjagun Tẹ́lẹ̀ Tí Wọ́n Di Olùwá Àlàáfíà
32 Àwọn Àwòrán Ilẹ̀ Tó Ń mú Kí Bíbélì Kíkà Rọrùn
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Hùwà sí Àwọn Àgbàlagbà? 22
Etí ti kún fún ìròyìn nípa bí àwọn èèyàn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ṣe ń pa àwọn àgbàlagbà tì, tí wọ́n sì ń fojú wọn rí màbo. Kí ni Bíbélì fi kọ́ni nípa bó ṣe yẹ ká máa hùwà sí àwọn àgbàlagbà?
Kí Ló Burú Nínú Mímutí Àmuyíràá? 25
Kí ló ń jẹ́ mímutí àmuyíràá? Kí lewu tó wà nínú káwọn ọ̀dọ́ máa mutí àmupara?