ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g 1/09 ojú ìwé 31
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
  • Jí!—2009
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ni Kò Tọ̀nà Nínú Àwòrán Yìí?
  • Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí
  • Àwọn Wo Ló Wà Lára Ìdílé Jésù?
  • ÌDÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2008
  • Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé
    Jí!—2011
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2008
  • Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé
    Jí!—2010
Àwọn Míì
Jí!—2009
g 1/09 ojú ìwé 31

Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?

Kí Ni Kò Tọ̀nà Nínú Àwòrán Yìí?

Tọ́ka sí ohun mẹ́ta nínú àwòrán yìí tó yàtọ̀ sí ohun tó wà nínú Jẹ́nẹ́sísì 7:1-9, 13-16, 23; 8:15-19.

1. ․․․․․

2. ․․․․․

AMỌ̀NÀ: Wo Léfítíkù 11:3 àti Diutarónómì 14:4.

3. ․․․․․

AMỌ̀NÀ: Wo Diutarónómì 14: 7-19.

FÚN ÌJÍRÒRÒ: Báwo làwọn ọmọ Nóà àtàwọn ìyàwó wọn ṣe ràn án lọ́wọ́? Báwo lo ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn ọmọ Nóà?

Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí

Dáhùn àwọn ìbéèrè yìí, kó o sì kọ (àwọn) ẹsẹ Bíbélì tó yẹ sínú àlàfo.

OJÚ ÌWÉ 6 Kí lẹni tó fẹ́ràn owó ò ní ní? Oníwàásù 5:․․․

OJÚ ÌWÉ 9 Àwọn wo ló máa láyọ̀? Mátíù 5:․․․

OJÚ ÌWÉ 18 Kí ni kò yẹ kéèyàn ṣe bó bá ń gbàdúrà? Mátíù 6:․․․

OJÚ ÌWÉ 28 Kí ló yẹ ká ṣe nípa àwọn àníyàn wa? 1 Pétérù 5:․․․

Àwọn Wo Ló Wà Lára Ìdílé Jésù?

Kọ́kọ́ wo ohun tá a kọ sínú amọ̀nà. Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a tọ́ka sí. Lẹ́yìn náà, kọ orúkọ tó tọ̀nà sínú àlàfo.

4. ․․․․․

AMỌ̀NÀ: Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àpẹẹrẹ burúkú ni bàbá mi fi lélẹ̀, síbẹ̀ mo jẹ́ ọba tó ń “bá a nìṣó ní fífà mọ́ Jèhófà.”

Ka 2 Àwọn Ọba 18:1-6.

5. ․․․․․

AMỌ̀NÀ: Mo ṣi agbára mi lò nípa títa ẹ̀jẹ̀ àwọn aláìmọwọ́-mẹsẹ̀ sílẹ̀ ní ìwọ̀n púpọ̀ gidigidi.

Ka 2 Àwọn Ọba 21:16.

6. ․․․․․

AMỌ̀NÀ: Mo tẹ̀ lé àpẹẹrẹ burúkú tí bàbá mi fi lélẹ̀, àwọn ìránṣẹ́ mi sì pa mí.

Ka 2 Àwọn Ọba 21:19-23.

ÌDÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ

1. Ọkọ̀ áàkì ò ní irú iwájú àti ẹ̀yìn tí ọkọ̀ ojú omi máa ń ní.

2. Nóà mú méje nínú àwọn ẹranko tí ó “mọ́,” irú bí àgùntàn, sínú áàkì.

3. Nóà mú onírúurú ẹranko tí “kò mọ́” ní méjì-méjì sínú ọkọ̀ áàkì.

4. Hesekáyà.—Mátíù 1:9.

5. Mánásè.—Mátíù 1:10.

6. Ámọ́nì.—Mátíù 1:10.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́