Ṣé Ó Wù Ẹ́ Kó O Mọ Bíbélì Dáadáa?
Kò pọn dandan kó o ní
Ọgbọ́n àrà ọ̀tọ̀
Owó
Tàbí kó o kàn gba ohun tí wọ́n bá ti sọ gbọ́
Ohun tó o nílò
“Agbára ìmọnúúrò.”—Róòmù 12:1
Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀
Àwọn ohun tó o máa kọ́ nínú Bíbélì máa yà ẹ́ lẹ́nu.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.
Ọgbọ́n àrà ọ̀tọ̀
Owó
Tàbí kó o kàn gba ohun tí wọ́n bá ti sọ gbọ́
“Agbára ìmọnúúrò.”—Róòmù 12:1
Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀
Àwọn ohun tó o máa kọ́ nínú Bíbélì máa yà ẹ́ lẹ́nu.