ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g19 No. 3 ojú ìwé 16
  • Ohun tó wà nínú ìwé yìí: Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí I?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun tó wà nínú ìwé yìí: Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí I?
  • Jí!—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìwé Àtijọ́ Kan Tó Wúlò Lóde Òní
  • Ìwé Tó Wúlò Jù Lọ Láyé
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2019
  • Ìwé Àtijọ́ Kan Tó Wúlò Lóde Òní
    Jí!—2019
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kí Bíbélì Máa Tọ́ Wa Sọ́nà?
    Jí!—2006
  • Ìwé Kan Tí Ó Wúlò Fún Ìgbésí Ayé Òde Òní
    Ìwé kan tí ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn
Àwọn Míì
Jí!—2019
g19 No. 3 ojú ìwé 16

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí: Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí i?

Ìwé Àtijọ́ Kan Tó Wúlò Lóde Òní

Obìnrin kan ń ka Bíbélì

Kì í ṣe ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ ìjọsìn nìkan ló wà nínú Bíbélì, àìmọye ìmọ̀ràn tó wúlò fún wa lóde òní ló wà níbẹ̀. Lára wọn ni:

  • Ọ̀rọ̀ ìlera

  • Bá a se lè jẹ́ onísùúrù

  • Bá a ṣe lè ní ìdílé aláyọ̀ àti ọ̀rẹ́ àtàtà

  • Gbígbọ́ bùkátà

  • Bá a ṣe lè sún mọ́ Ọlọ́run

Ìwé Tó Wúlò Jù Lọ Láyé

Láti ọdúnmọ́dún ni Bíbélì ti ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ tó sì ń mú kí ìgbésí ayé wọn dáa sí i. Lónìí, Bíbélì wà ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún èdè. Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè jàǹfààní látinú ọgbọ́n tó wà nínú rẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́