ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • bt ojú ìwé 100
  • “Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”
  • “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Inúnibíni Tó Lágbára Sí Ìjọ”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Bá A Ṣe Ṣètò Ìjọ àti Bá A Ṣe Ń Darí Rẹ̀
    A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
  • Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ń Mú Ká Wà Létòletò
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Àwọn Míì
“Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
bt ojú ìwé 100
Sílà àti Júdásì ń ka àkájọ ìwé fún ìjọ tó wà ní Áńtíókù ti Síríà.

APÁ 5 • ÌṢE 15:1-35

“Àwọn Àpọ́sítélì Àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”

ÌṢE 15:6

Awuyewuye kan tó lágbára wáyé tó lè mú kó nira fáwọn ará láti wà níṣọ̀kan, kí àlàáfíà sì wà láàárín wọn. Ta ló máa fún wọn ní ìtọ́ni tó ṣeé gbára lé táá jẹ́ kí wọ́n lè yanjú awuyewuye náà? Ní apá yìí, a máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Ọlọ́run ṣe ṣètò ìjọ ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní, àá sì rí bí ìyẹn ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ rere fáwa èèyàn Ọlọ́run lónìí.

Alábòójútó àyíká kan ń sọ àsọyé fáwọn ará.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́