ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ll apá 1 ojú ìwé 4-5
  • Báwo La Ṣe Lè Tẹ́tí sí Ọlọ́run?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Báwo La Ṣe Lè Tẹ́tí sí Ọlọ́run?
  • Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Apa 1
    Tẹ́tí sí Ọlọ́run
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Bá A Ṣe Lè Dẹni Tó Lẹ́bùn Fífarabalẹ̀ Títẹ́tí Síni
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
Àwọn Míì
Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
ll apá 1 ojú ìwé 4-5

APÁ 1

Báwo La Ṣe Lè Tẹ́tí sí Ọlọ́run?

Bíbélì ni Ọlọ́run fi ń bá wa sọ̀rọ̀. 2 Tímótì 3:16

Látorí ìtẹ́ rẹ̀ ní ọ̀run, Jèhófà ń mí sí àwọn èèyàn kí wọ́n lè kọ Bíbélì

Ọlọ́run tòótọ́ mú kí àwọn èèyàn kọ èrò òun sínú ìwé mímọ́ kan. Ìwé náà ni Bíbélì. Àwọn ohun tó ṣe pàtàkì tí Ọlọ́run fẹ́ kí o mọ̀ ló wà nínú rẹ̀.

Ọlọ́run mọ ohun tó dáa jù lọ fún wa, òun sì ni Orísun gbogbo ọgbọ́n. Tí o bá ń tẹ́tí sí i, ó dájú pé wàá di ọlọ́gbọ́n.​—Òwe 1:5.

Bíbélì wà ní oríṣiríṣi èdè; ọkùnrin kan ń ka Bíbélì ní èdè rẹ̀

Ọlọ́run fẹ́ kí gbogbo èèyàn tó wà láyé máa ka Bíbélì. Ó ti wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè báyìí.

Tí o bá fẹ́ tẹ́tí sí Ọlọ́run, o gbọ́dọ̀ máa ka Bíbélì, kí o sì lóye rẹ̀.

Ibi gbogbo ni àwọn èèyàn ti ń tẹ́tí sí Ọlọ́run. Mátíù 28:19

Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ń ka Bíbélì fún ọkùnrin kan, ó wá ń kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kí o lè lóye Bíbélì.

Kárí ayé là ń fi òtítọ́ nípa Ọlọ́run kọ́ àwọn èèyàn.

Ìpàdé ń lọ lọ́wọ́ ní Gbọ̀ngàn Ìjọba àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

A kì í gba owó lọ́wọ́ àwọn èèyàn torí pé à ń kọ́ wọn lẹ́kọ̀ọ́. O tún lè kẹ́kọ̀ọ́ nípa Ọlọ́run tí o bá lọ sí Gbọ̀ngàn Ìjọba àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà nítòsí rẹ.

  • Òtítọ́ ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.​—Jòhánù 17:17.

  • Kí nìdí tó fi yẹ ká gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run?​—Nọ́ńbà 23:19.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́