ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ll apá 7 ojú ìwé 16-17
  • Ta Ni Jésù?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ta Ni Jésù?
  • Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Apa 7
    Tẹ́tí sí Ọlọ́run
  • Ta Ni Jésù Kristi?
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ta Ni Jésù Kristi?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
Àwọn Míì
Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
ll apá 7 ojú ìwé 16-17

APÁ 7

Ta Ni Jésù?

Jèhófà rán Jésù wá sí ayé. 1 Jòhánù 4:9

Jésù wà ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run ní ọ̀run

Ká tó lè múnú Jèhófà dùn, a gbọ́dọ̀ tẹ́tí sí ẹnì kan tó tún ṣe pàtàkì. Tipẹ́tipẹ́ kí Jèhófà tó dá Ádámù ló ti dá áńgẹ́lì kan tó lágbára sí ọ̀run.

Màríà rèé nígbà tó lóyún àti lẹ́yìn tó bí Jésù

Nígbà tó yá, Jèhófà mú kí wúńdíá kan tó ń jẹ́ Màríà bí ẹni yìí sí ìlú Bẹ́tílẹ́hẹ́mù. Wọ́n sọ orúkọ ọmọ náà ní Jésù.​—Jòhánù 6:38.

Jésù ń kọ́ àwọn èèyàn nípa Jèhófà

Nígbà tí Jésù jẹ́ èèyàn ní ayé, ó gbé àwọn ìwà Ọlọ́run yọ láìkù síbì kan. Ó jẹ́ onínúure, ó nífẹ̀ẹ́, ó sì ṣeé sún mọ́. Ó kọ́ àwọn èèyàn ní òtítọ́ nípa Jèhófà láìbẹ̀rù.

Ohun rere ni Jésù ṣe, àmọ́ àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀. 1 Pétérù 2:​21-24

Jésù jí ọmọbìnrin kan tó ti kú dìde, ó sì mú ọkùnrin kan tó ń ṣàìsàn lára dá

Àwọn aṣáájú ìsìn kórìíra Jésù torí pé ó tú àṣírí àwọn ẹ̀kọ́ èké àti ìwà ibi wọn.

Jésù tún mú àwọn aláìsàn lára dá, ó sì jí àwọn kan tó ti kú dìde.

Wọ́n lu Jésù, wọ́n sì pa á

Àwọn aṣáájú ìsìn mú kí àwọn ará Róòmù na Jésù kí wọ́n sì pa á.

  • Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé kéèyàn mọ Jésù?​—Jòhánù 17:3.

  • Kí ni Jésù ń ṣe ní ọ̀run kó tó wá sí ayé?​—Kólósè 1:​15-17.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́