ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • jy ojú ìwé 320
  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Kan Nípa Mèsáyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Kan Nípa Mèsáyà
  • Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Fẹ̀rí Hàn Pé Jésù Ni Mèsáyà Náà?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Jésù Kristi Ni Mèsáyà Tí Ọlọ́run Ṣèlérí
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • Mèsáyà
    Jí!—2015
  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
jy ojú ìwé 320

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Kan Nípa Mèsáyà

ÌṢẸ̀LẸ̀

ÀSỌTẸ́LẸ̀

ÌMÚṢẸ

ORÍ

Wọ́n bí i ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù

Míkà 5:2

Lúùkù 2:1-6

5, 7, 67

Wọ́n gbé e lọ sí Íjíbítì, wọ́n sì gbé e pa dà

Hósíà 11:1

Mátíù 2:13-15, 19, 20

8

Àwọn ìyá ń sunkún nítorí àwọn ọmọkùnrin wọn tí wọ́n pa nígbà tí wọ́n fẹ́ pa Jésù ní kékeré

Jeremáyà 31:15

Mátíù 2:17, 18

8

Ìkéde òmìnira fún àwọn ẹrú

Àìsáyà 61:1, 2

Lúùkù 4:17-21

21

Ó ń gbé ní Kápánáúmù ti Gálílì

Àìsáyà 9:1, 2

Mátíù 4:13-17

22, 67

Ó wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn

Àìsáyà 53:4

Mátíù 8:16, 17

23

Kò ní báàyàn jà lójú ọ̀nà

Àìsáyà 42:1-4

Mátíù 12:16-21

33

Ó máa fi àpèjúwe kọ́ni

Sáàmù 78:2; Àìsáyà 6:9, 10

Mátíù 13:13-15, 34, 35

43

Ó máa gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọ Jerúsálẹ́mù

Sekaráyà 9:9

Mátíù 21:1-9

102

Ọ̀pọ̀ ni kò gbà á gbọ́

Àìsáyà 6:10; 53:1

Jòhánù 12:37, 38

104

Ẹni tó fọkàn tán dà á

Sáàmù 41:9

Jòhánù 13:18, 21

117

Àwọn ọmọ ẹ̀yìn tú ká, wọ́n sì pa á tì

Sekaráyà 13:7

Mátíù 26:31, 54-56

118, 124

Wọ́n máa kórìíra rẹ̀ láìnídìí

Sáàmù 35:19; 69:4

Jòhánù 15:24, 25

120

Àwọn ọmọ ogun pín ẹ̀wù rẹ̀ láàárín ara wọn

Sáàmù 22:18

Jòhánù 19:23, 24

131

Òùngbẹ gbẹ ẹ́ nígbà tó wà lórí òpó igi

Sáàmù 22:15

Jòhánù 19:28

132

Wọ́n gún un lẹ́yìn tó ti kú

Sekaráyà 12:10

Jòhánù 19:34, 37

133

Kò sí ìkankan nínú egungun rẹ̀ tí ó ṣẹ́ kó tó kú

Sáàmù 34:20

Jòhánù 19:36

133

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́