ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 May ojú ìwé 6
  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Fẹ̀rí Hàn Pé Jésù Ni Mèsáyà Náà?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Jésù Kristi Ni Mèsáyà Tí Ọlọ́run Ṣèlérí
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • Wọ́n Rí Mèsáyà!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Kan Nípa Mèsáyà
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 May ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 19-25

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà

ÌWÉ MÍMỌ́

ÀSỌTẸ́LẸ̀

ÌMÚṢẸ ÀSỌTẸ́LẸ̀

Sáàmù 22:1

Bíi pé Ọlọ́run fi í sílẹ̀

Mátíù 27:46; Máàkù 15:34

Sáàmù 22:7, 8

Wọ́n kẹ́gàn rẹ̀ lórí òpó igi oró

Mátíù 27:39-43

Sáàmù 22:16

Wọ́n kàn-án mọ́gi

Mátíù 27:31; Máàkù 15:25; Jòhánù 20:25

Sáàmù 22:18

Wọ́n ṣẹ́ kèké lé aṣọ rẹ̀

Mátíù 27:35

Sáàmù 22:22

Ó mú ipò iwájú nínú pípolongo orúkọ Jèhófà

Jòhánù 17:6

Ẹnì kan tó ń pẹ̀gàn Jésù gbá a létí; nígbà tó yá, àwọn èèyàn ń ṣọ̀fọ̀ Jésù tó kú lórí òpó igi oró
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́