ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 74
  • Jẹ́ Ká Jọ Kọ Orin Ìjọba Náà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Ká Jọ Kọ Orin Ìjọba Náà
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Dara Pọ̀ Nínú Kíkọ Orin Ìjọba Náà!
    Kọrin sí Jèhófà
  • Jèhófà Ni Ìyìn àti Ògo Yẹ!
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pẹ̀lú Gbogbo Ọkàn Rẹ
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2019-2020—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Fojú Inú Wo Ìgbà Tí Gbogbo Nǹkan Yóò Di Tuntun
    Kọrin sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 74

ORIN 74

Jẹ́ Ká Jọ Kọ Orin Ìjọba Náà

Bíi Ti Orí Ìwé

(Sáàmù 98:1)

  1. 1. Orin ayọ̀ ìṣẹ́gun ni orin yìí.

    Ó ń gbé Olódùmarè Ọba ga.

    Jẹ́ ká jọ kọ ọ́; ó ń fún wa ní ìrètí,

    Ó sì ń kọ́ wa pé ká dúró ṣinṣin.

    (ÈGBÈ)

    Ẹ wọlé wá síwájú Jáà.

    Ẹ kéde pé Jésù lọba.

    Mọ orin yìí, orin nípa ‘jọba náà.

    Wá jọ́sìn Jáà, kó o yin orúkọ rẹ̀.

  2. 2. À ń forin tuntun yìí kéde fáráyé

    Pé Jésù Kristi ti ń jọba lọ́run.

    Àwọn kan wà tó máa bá Jésù jọba.

    Ọlọ́run ti sọ wọ́n di àtúnbí.

    (ÈGBÈ)

    Ẹ wọlé wá síwájú Jáà.

    Ẹ kéde pé Jésù lọba.

    Mọ orin yìí, orin nípa ‘jọba náà.

    Wá jọ́sìn Jáà, kó o yin orúkọ rẹ̀.

  3. 3. Àwọn onírẹ̀lẹ̀ lè mọ orin yìí.

    Ọ̀rọ̀ rẹ̀ rọrùn, ó sì dùn mọ́ni.

    Ọ̀pọ̀ ti mọ orin yìí kárí ayé,

    Wọ́n sì tún ń ké sí àwọn mìíràn pé:

    (ÈGBÈ)

    Ẹ wọlé wá síwájú Jáà.

    Ẹ kéde pé Jésù lọba.

    Mọ orin yìí, orin nípa ‘jọba náà.

    Wá jọ́sìn Jáà, kó o yin orúkọ rẹ̀.

(Tún wo Sm. 95:6; 1 Pét. 2:​9, 10; Ìfi. 12:10.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́