ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm20 ojú ìwé 2-3
  • Friday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Friday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀!
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
  • “Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà”
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2020-2021—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
CO-pgm20 ojú ìwé 2-3
Àwòrán: 1. Wòlí ì Málákì. 2. Òdòdó. 3. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà méjì láti ilẹ̀ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ jọ ń ṣiṣẹ́ lóde ẹ̀rí. Wọ́n ń rẹ́rìn-ín, wọ́n sì bọ ara wọn lọ́wọ́. 4. Àwọn tọkọtaya àgbàlagbà kan di ara wọn mú, wọ́n sì ń rẹ́rìn-ín sí ara wọn.

Friday

“Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo nínú Olúwa. Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo sọ pé, Ẹ máa yọ̀!”​—Fílípì 4:4

ÀÁRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 111 àti Àdúrà

  • 9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Ìdí Tí Jèhófà Fi Jẹ́ “Ọlọ́run Aláyọ̀” (1 Tímótì 1:11)

  • 10:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kí Lá Jẹ́ Kó O Láyọ̀?

    • • Jẹ́ Kí Ohun Díẹ̀ Tẹ́ Ẹ Lọ́rùn (Oníwàásù 5:12)

    • • Ẹ̀rí Ọkàn Tó Mọ́ (Sáàmù 19:8)

    • • Iṣẹ́ Tó Ń Fini Lọ́kàn Balẹ̀ (Oníwàásù 4:6; 1 Kọ́ríńtì 15:58)

    • • Àwọn Ọ̀rẹ́ Tòótọ́ (Òwe 18:24; 19:​4, 6, 7)

  • 11:05 Orin 89 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: ‘Jèhófà Mú Kí Wọ́n Máa Yọ̀’ (Ẹ́sírà 1:1–6:22; Hágáì 1:2-11; 2:3-9; Sekaráyà 1:12-16; 2:7-9; 3:1, 2; 4:6, 7)

  • 11:45 Máa Yọ̀ Nítorí Àwọn Iṣẹ́ Ìgbàlà Jèhófà (Sáàmù 9:14; 34:19; 67:1, 2; Àìsáyà 12:2)

  • 12:15 Orin 148 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀SÁN

  • 1:30 Fídíò Orin

  • 1:40 Orin 131

  • 1:45 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ìdílé Rẹ

    • • Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ìyàwó Yín (Òwe 5:​18, 19; 1 Pétérù 3:7)

    • • Ẹ̀yin Aya, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ọkọ Yín (Òwe 14:1)

    • • Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Ọmọ Yín (Òwe 23:​24, 25)

    • • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Òbí Yín (Òwe 23:22)

  • 2:50 Orin 135 àti Ìfilọ̀

  • 3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Fẹ́ Ká Máa Yọ̀

    • • Àwọn Òdòdó Tó Rẹwà (Sáàmù 111:2; Mátíù 6:​28-30)

    • • Oúnjẹ Aládùn (Oníwàásù 3:​12, 13; Mátíù 4:4)

    • • Àwọ̀ Mèremère (Sáàmù 94:9)

    • • Ara Èèyàn (Ìṣe 17:28; Éfésù 4:16)

    • • Ohùn Tó Ń Tuni Lára (Òwe 20:12; Àìsáyà 30:21)

    • • Àwọn Ẹranko Àgbàyanu (Jẹ́nẹ́sísì 1:26)

  • 4:00 Kí Nìdí Tí ‘Àwọn Tó Ń Wá Àlàáfíà Fi Máa Ń Láyọ̀’? (Òwe 12:20; Jémíìsì 3:13-18; 1 Pétérù 3:10, 11)

  • 4:20 Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà Lohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀ Tó Ga Jù Lọ! (Sáàmù 25:14; Hábákúkù 3:​17, 18)

  • 4:55 Orin 28 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́