ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm17 ojú ìwé 4-5
  • Saturday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Saturday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
CO-pgm17 ojú ìwé 4-5
Àwòrán tó jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a máa gbádùn ní òwúrọ̀ ọjọ́ Saturday nínú ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2017.

Saturday

“Ẹ máa yọ̀ nínú ìrètí. Ẹ máa ní ìfaradà lábẹ́ ìpọ́njú” ​—RÓÒMÙ 12:12

ÒWÚRỌ̀

  • 8:20 [10:50] Fídíò Orin

  • 8:30 [11:00] Orin 44 àti Àdúrà

  • 8:40 [11:10] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Jèhófà Ṣe Ń “Pèsè Ìfaradà àti Ìtùnú” fún . . .

    • Àwọn Aláìlera Àtàwọn Tó Sorí Kọ́ (Róòmù 15:​4, 5; 1 Tẹsalóníkà 5:14; 1 Pétérù 5:​7-10)

    • Àwọn Aláìní (1 Tímótì 6:18)

    • Àwọn Ọmọ “Aláìníbaba” (Sáàmù 82:3)

    • Àwọn Àgbàlagbà (Léfítíkù 19:32)

  • 9:50 [12:20] Orin 138 àti Ìfilọ̀

  • 10:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí

    • “Ní Ìtẹ́lọ́rùn Pẹ̀lú Àwọn Nǹkan Ìsinsìnyí” (Hébérù 13:5; Sáàmù 127:​1, 2)

    • Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ “Ohun Tí Ó Jẹ́ Ibi” (Róòmù 16:19; Sáàmù 127:3)

    • Ẹ Tọ́ Àwọn Ọmọ Yín ‘Ní Ọ̀nà Tí Wọn Yóò Tọ̀’ (Òwe 22:​3, 6; Sáàmù 127:​4, 5)

  • 10:45 [12:30] ÌRÌBỌMI: Ẹ Má Ṣe “Bẹ̀rù”! (1 Pétérù 3:​6, 12, 14)

  • 11:15 [1:00] Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi

Àwòrán tó jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a máa gbádùn ní ọ̀sán ọjọ́ Saturday nínú ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2017.

Ọ̀SÁN

  • 12:35 [2:00] Fídíò Orin

  • 12:45 [2:10] Orin 126

  • 12:50 [2:15] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ “Àwọn Tí Wọ́n Lo Ìfaradà”

    • Jósẹ́fù (Jẹ́nẹ́sísì 37:​23-28; 39:​17-20; Jákọ́bù 5:11)

    • Jóòbù (Jóòbù 10:12; 30:​9, 10)

    • Ọmọbìnrin Jẹ́fútà (Àwọn Onídàájọ́ 11:​36-40)

    • Jeremáyà (Jeremáyà 1:​8, 9)

  • 1:35 [3:00] ÀWÒKẸ́KỌ̀Ọ́: Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì​—Apá Kejì (Lúùkù 17:​28-33)

  • 2:05 [3:30] Orin 111 àti Ìfilọ̀

  • 2:15 [3:40] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ìfaradà Lára Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá

    • Ràkúnmí (Júúdà 20)

    • Igi Orí Òkè (Kólósè 2:​6, 7; 1 Pétérù 5:​9, 10)

    • Labalábá (2 Kọ́ríńtì 4:16)

    • Ẹyẹ Ilẹ̀ Olótùútù (1 Kọ́ríńtì 13:7)

    • Ẹyẹ Etí Omi (Hébérù 10:39)

    • Igi Bọn-Ọ̀n-Ní (Éfésù 6:13)

  • 3:15 [4:40] Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ìfaradà Yín Ń Mú Inú Jèhófà Dùn! (Òwe 27:11)

  • 3:50 [5:15] Orin 135 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́