Friday
“ỌLỌ́RUN TI KỌ́ YÍN LÁTI MÁA NÍFẸ̀Ẹ́ ARA YÍN”—1 TẸSALÓNÍKÀ 4:9
ÒWÚRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 105 àti Àdúrà
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Nìdí Tí Ìfẹ́ Kò Fi Ní Yẹ̀ Láé? (Róòmù 8:38, 39; 1 Kọ́ríńtì 13:1-3, 8, 13)
10:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Ṣe Gbọ́kàn Lé Àwọn Nǹkan Tó Máa Dópin!
Ọrọ̀ (Mátíù 6:24)
Ipò àti Òkìkí (Oníwàásù 2:16; Róòmù 12:16)
Ọgbọ́n Èèyàn (Róòmù 12:1, 2)
Okun àti Ẹwà (Òwe 31:30; 1 Pétérù 3:3, 4)
11:05 Orin 40 àti Ìfilọ̀
11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Jèhófà Ń Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn (Jẹ́nẹ́sísì 37:1-36; 39:1–47:12)
11:45 Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Ọmọ Rẹ̀ (Mátíù 25:40; Jòhánù 14:21; 16:27)
12:15 Orin 20 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:25 Fídíò Orin
1:35 Orin 107
1:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Rẹ Yẹ̀ Láé . . .
Bí Wọn Ò Bá Tiẹ̀ Fi Ìfẹ́ Tọ́ Ẹ Dàgbà (Sáàmù 27:10)
Bó O Tiẹ̀ Ń Kojú Ìṣòro Níbi Iṣẹ́ (1 Pétérù 2:18-20)
Bó O Tiẹ̀ Ń Kojú Ìṣòro Nílé Ìwé (1 Tímótì 4:12)
Bó O Tiẹ̀ Ń Ṣàìsàn Tó Le Koko (2 Kọ́ríńtì 12:9, 10)
Tó O Bá Tiẹ̀ Jẹ́ Tálákà (Fílípì 4:12, 13)
Bí Àwọn Mọ̀lẹ́bí Rẹ Tiẹ̀ Ń Ta Kò Ẹ́ (Mátíù 5:44)
2:50 Orin 141 àti Ìfilọ̀
3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Wa
Àwọn Ọ̀run (Sáàmù 8:3, 4; 33:6)
Ayé (Sáàmù 37:29; 115:16)
Àwọn Ewéko (Jẹ́nẹ́sísì 1:11, 29; 2:9, 15; Ìṣe 14:16, 17)
Àwọn Ẹranko (Jẹ́nẹ́sísì 1:27; Mátíù 6:26)
Ara Èèyàn (Sáàmù 139:14; Oníwàásù 3:11)
3:55 “Àwọn Tí Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ló Máa Ń Bá Wí” (Hébérù 12:5-11; Sáàmù 19:7, 8, 11)
4:15 “Ẹ Fi Ìfẹ́ Wọ Ara Yín Láṣọ” (Kólósè 3:12-14)
4:50 Orin 130 àti Àdúrà Ìparí