Sunday
“. . . nígbà náà ni òpin yóò dé”—Mátíù 24:14
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 84 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Fara Wé Àwọn Tó Gba Ìhìn Rere Gbọ́
• Sekaráyà (Hébérù 12:5, 6)
• Èlísábẹ́tì (1 Tẹsalóníkà 5:11)
• Màríà (Sáàmù 77:12)
• Jósẹ́fù (Òwe 1:5)
• Síméónì àti Ánà (1 Kíróníkà 16:34)
• Jésù (Jòhánù 8:31, 32)
11:05 Orin 65 àti Ìfilọ̀
11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ìdí tí Ìròyìn Burúkú Ò Fi Bà Wá Lẹ́rù (Sáàmù 112:1-10)
11:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
12:15 Orin 61 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 122
1:50 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI Ń SỌ ÌTÀN: “A Ò Ní Fi Falẹ̀ Mọ́” (Ìfihàn 10:6)
2:20 Orin 126 àti Ìfilọ̀
2:30 Kí Lo Rí Kọ́?
2:40 ‘Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká ‘Di Ìhìn Rere Mú Ṣinṣin,’ Báwo La Ṣe Lè Ṣe Bẹ́ẹ̀? (1 Kọ́ríńtì 2:16; 15:1, 2, 58; Máàkù 6:30-34)
3:30 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí