ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm17 ojú ìwé 6-7
  • Sunday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sunday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
CO-pgm17 ojú ìwé 6-7
Àwòrán tó jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a máa gbádùn ní òwúrọ̀ ọjọ́ Sunday nínú ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2017.

Sunday

“Ẹni tí ó bá fara dà á dé òpin ni ẹni tí a ó gbà là”​—MÁTÍÙ 24:13

ÒWÚRỌ̀

  • 8:20 Fídíò Orin

  • 8:30 Orin 121 àti Àdúrà

  • 8:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’

    • Sáré Kó O Lè Gba Èrè! (1 Kọ́ríńtì 9:24)

    • Máa Kọ́ Ara Rẹ (1 Kọ́ríńtì 9:​25-27)

    • Fi Àwọn Ẹrù Tí Kò Pọndandan Sílẹ̀ (Hébérù 12:1)

    • Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Àpẹẹrẹ Rere (Hébérù 12:​2, 3)

    • Máa Jẹ Oúnjẹ Tó Ń Ṣara Lóore (Hébérù 5:​12-14)

    • Máa Mu Omi Dáadáa (Ìṣípayá 22:17)

    • Máa Tẹ̀ Lé Òfin Eré Sísá (2 Tímótì 2:5)

    • Jẹ́ Kó Dá Ọ Lójú Pé Wàá Gba Èrè (Róòmù 15:13)

  • 10:10 Orin 141 àti Ìfilọ̀

  • 10:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Má Ṣe Sọ̀rètí Nù! (Aísáyà 48:17; Jeremáyà 29:11)

  • 10:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 11:20 Orin 20 àti Àkókò Ìsinmi

Àwòrán tó jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a máa gbádùn ní ọ̀sán ọjọ́ Sunday nínú ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2017.

Ọ̀SÁN

  • 12:35 Fídíò Orin

  • 12:45 Orin 57

  • 12:50 ÀWÒKẸ́KỌ̀Ọ́: Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì​—Apá Kẹta (Lúùkù 17:​28-33)

  • 1:20 Orin 54 àti Ìfilọ̀

  • 1:30 ‘Máa Fojú Sọ́nà . . . Kò Ní Pẹ́ Mọ́!’ (Hábákúkù 2:3)

  • 2:30 Orin 129 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́