Sunday
“Jọ́sìn Baba ní ẹ̀mí àti òtítọ́”—Jòhánù 4:23
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 140 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Jésù
• A Gbọ́dọ̀ “Bí Ẹnì Kan Látinú Omi àti Ẹ̀mí” (Jòhánù 3:3, 5)
• “Kò Sí Èèyàn Kankan Tó Tíì Gòkè Lọ Sọ́run” (Jòhánù 3:13)
• “Wá Sínú Ìmọ́lẹ̀” (Jòhánù 3:19-21)
• “Èmi Ni” (Jòhánù 4:25, 26)
• “Oúnjẹ Mi Ni” (Jòhánù 4:34)
• “Àwọn Pápá ti Funfun . . . Wọ́n ti Tó Kórè” (Jòhánù 4:35)
11:05 Orin 37 àti Ìfilọ̀
11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ṣé Ò Ń Jọ́sìn Ohun Tó O Mọ̀? (Jòhánù 4:20-24)
11:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
12:15 Orin 84 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 77
1:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:
Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 3
“Èmi Ni” (Jòhánù 3:1–4:54; Mátíù 4:12-20; Máàkù 1:19, 20; Lúùkù 4:16–5:11)
2:35 Orin 20 àti Ìfilọ̀
2:45 Kí Lo Rí Kọ́?
2:55 Má Ṣe Kúrò Nínú Tẹ́ńpìlì Ńlá Tẹ̀mí Jèhófà! (Hébérù 10:21-25; 13:15, 16; 1 Pétérù 1:14-16; 2:21)
3:45 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí