Saturday
“Ìtara ilé rẹ máa gbà mí lọ́kàn”—Jòhánù 2:17
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 93 àti Àdúrà
9:40 “Kí Lẹ̀ Ń Wá?” (Jòhánù 1:38)
9:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:
Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 2
“Èyí ni Ọmọ Mi”—Apá Kejì (Jòhánù 1:19–2:25)
10:20 Orin 54 àti Ìfilọ̀
10:30 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Ìjọsìn Mímọ́!
• Jòhánù Arinibọmi (Mátíù 11:7-10)
• Áńdérù (Jòhánù 1:35-42)
• Pétérù (Lúùkù 5:4-11)
• Jòhánù (Mátíù 20:20, 21)
• Jémíìsì (Máàkù 3:17)
• Fílípì (Jòhánù 1:43)
• Nàtáníẹ́lì (Jòhánù 1:45-47)
11:35 ÌRÌBỌMI: Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ṣèrìbọmi? (Málákì 3:17; Ìṣe 19:4; 1 Kọ́ríńtì 10:1, 2)
12:05 Orin 52 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 36
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nínú Iṣẹ́ Ìyanu Tí Jésù Kọ́kọ́ Ṣe
• Máa Ṣàánú (Gálátíà 6:10; 1 Jòhánù 3:17)
• Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ (Mátíù 6:2-4; 1 Pétérù 5:5)
• Jẹ́ Ọ̀làwọ́ (Diutarónómì 15:7, 8; Lúùkù 6:38)
2:20 Báwo Ni “Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run” Ṣe Kó Ẹ̀ṣẹ̀ Aráyé Lọ? (Jòhánù 1:29; 3:14-16)
2:45 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Ṣẹ!—Apá Kejì
• Ìtara Ilé Jèhófà Gbà Á Lọ́kàn (Sáàmù 69:9; Jòhánù 2:13-17)
• Ó Kéde “Ìhìn Rere fún Àwọn Oníwà Pẹ̀lẹ́” (Àìsáyà 61:1, 2)
• Ó Tan “Ìmọ́lẹ̀ Tó Tàn Yòò” ní Gálílì (Àìsáyà 9:1, 2)
3:20 Orin 117 àti Ìfilọ̀
3:30 “Ẹ Kó Àwọn Nǹkan Yìí Kúrò Níbí!” (Jòhánù 2:13-16)
4:00 ‘Màá Kọ́ Ọ’ (Jòhánù 2:18-22)
4:35 Orin 75 àti Àdúrà Ìparí