Friday
‘Ìhìn rere ayọ̀ ńláǹlà . . . , èyí tí gbogbo èèyàn máa ní’—Lúùkù 2:10
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 150 àti Àdúrà
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Nìdí Tá A Fi Nílò Ìhìn Rere? (1 Kọ́ríńtì 9:16; 1 Tímótì 1:12)
10:10 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:
Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 1
Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé—Apá Kìíní (Mátíù 1:18-25; Lúùkù 1:1-80; Jòhánù 1:1-5)
10:45 Orin 96 àti Ìfilọ̀
10:55 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: “Ẹ̀mí Mímọ́ Ló Darí Wọn”
• Mátíù (2 Pétérù 1:21)
• Máàkù (Máàkù 10:21)
• Lúùkù (Lúùkù 1:1-4)
• Jòhánù (Jòhánù 20:31)
12:10 Orin 110 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 117
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Gba Òtítọ́ Nípa Jésù Gbọ́
• Ọ̀rọ̀ Náà (Jòhánù 1:1; Fílípì 2:8-11)
• Orúkọ Ẹ̀ (Ìṣe 4:12)
• Bí Wọ́n Ṣe Bí I (Mátíù 2:1, 2, 7-12, 16)
2:30 Orin 99 àti Ìfilọ̀
2:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nípa Ibi tí Jésù Gbé
• Ilẹ̀ (Diutarónómì 8:7)
• Àwọn Ẹranko (Lúùkù 2:8, 24)
• Oúnjẹ (Lúùkù 11:3; 1 Kọ́ríńtì 10:31)
• Bí Ìgbésí Ayé Ṣe Rí (Fílípì 1:10)
• Àwọn Aládùúgbò (Diutarónómì 22:4)
• Ẹ̀kọ́ (Diutarónómì 6:6, 7)
• Ìjọsìn (Diutarónómì 16:15, 16)
4:15 Kí Ni “Ìhìn Rere Àìnípẹ̀kun? (Ìfihàn 14:6, 7)
4:50 Orin 66 àti Àdúrà Ìparí