Friday
“Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni o gbọ́dọ̀ jọ́sìn”—Mátíù 4:10
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 74 àti Àdúrà
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Ni Ìjọsìn Mímọ́? (Àìsáyà 48:17; Málákì 3:16)
10:10 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:
Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 2
“Èyí ni Ọmọ Mi”—Apá Kìíní (Mátíù 3:1–4:11; Máàkù 1:12, 13; Lúùkù 3:1–4:7; Jòhánù 1:7, 8)
10:40 Orin 122 àti Ìfilọ̀
10:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Ṣẹ!—Apá Kìíní
• Ọlọ́run Pè É Ní Ọmọ Rẹ̀ (Sáàmù 2:7; Mátíù 3:16, 17; Ìṣe 13:33, 34)
• Ìdílé Dáfídì Ló Ti Wá (2 Sámúẹ́lì 7:12, 13; Mátíù 1:1, 2, 6)
• Ó Di “Mèsáyà Aṣáájú” (Dáníẹ́lì 9:25; Lúùkù 3:1, 2, 21-23)
11:45 Ta Ló Ń Ṣàkóso Ayé Yìí Gan-an? (Máàkù 12:17; Lúùkù 4:5-8; Jòhánù 18:36)
12:15 Orin 22 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 121
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Bí Jésù Ṣe Dá Sátánì Lóhùn!
• Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Kó O Gbára Lé (Mátíù 4:1-4)
• Má Ṣe Dán Jèhófà Wò (Mátíù 4:5-7)
• Jèhófà Nìkan Ni Kó O Jọ́sìn (Mátíù 4:10; Lúùkù 4:5-7)
• Fi Ìgboyà Sọ Ohun Tó O Gbà Gbọ́ (1 Pétérù 3:15)
2:50 Orin 97 àti Ìfilọ̀
3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ohun Tá A Kọ́ Nípa Ibi tí Jésù Dé
• Aginjù Jùdíà (Mátíù 3:1-4; Lúùkù 4:1)
• Àfonífojì Jọ́dánì (Mátíù 3:13-15; Jòhánù 1:27, 30)
• Jerúsálẹ́mù (Mátíù 23:37, 38)
• Samáríà (Jòhánù 4:7-9, 40-42)
• Gálílì (Mátíù 13:54-57)
• Foníṣíà (Lúùkù 4:25, 26)
• Síríà (Lúùkù 4:27)
4:10 Kí Ni Jésù Ń Rí Lára Rẹ? (Jòhánù 2:25)
4:45 Orin 34 àti Àdúrà Ìparí