ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm24 ojú ìwé 4-5
  • Saturday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Saturday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2022
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
CO-pgm24 ojú ìwé 4-5
Àwòrán: Àwọn nǹkan tá a máa gbádùn lọ́jọ́ Saturday. 1. Jósẹ́fù àti Màríà gbé Jésù dání nígbà tó wà lọ́mọ ọwọ́. 2. Ọba Hẹ́rọ́dù. 3. Tọkọtaya méjì wà lóde ìwàásù.

Saturday

“Ẹ máa kéde ìhìn rere ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́”​—Sáàmù 96:2

Àárọ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 53 àti Àdúrà

  • 9:40 “Mo Gbọ́dọ̀ . . . Kéde Ìhìn Rere Ìjọba Ọlọ́run” (Lúùkù 4:43)

  • 9:50 FÍDÍÒ ÌTÀN BÍBÉLÌ:

    Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 1

    Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé—Apá Kejì (Mátíù 2:1-23; Lúùkù 2:1-38, 41-52; Jòhánù 1:9)

  • 10:25 Orin 69 àti Ìfilọ̀

  • 10:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Ṣẹ!

    • • Ìránṣẹ́ kan wá ṣáájú rẹ̀ (Málákì 3:1; 4:5; Mátíù 11:10-14)

    • • Wúńdíá ló bí i (Àìsáyà 7:14; Mátíù 1:18, 22, 23)

    • • Wọ́n bí i sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù (Míkà 5:2; Lúùkù 2:4-7)

    • • Ohunkóhun ò ṣe é ní kékeré (Hósíà 11:1; Mátíù 2:13-15)

    • • Wọ́n pè é ní ará Násárẹ́tì (Àìsáyà 11:1, 2; Mátíù 2:23)

    • • Ó dé ní Àkókò tí Bíbélì sọ (Dáníẹ́lì 9:25; Lúùkù 3:1, 2, 21, 22)

  • 11:40 ÌRÌBỌMI: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere” (2 Kọ́ríńtì 9:13; 1 Tímótì 4:12-16; Hébérù 13:17)

  • 12:10 Orin 24 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀sán

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 83

  • 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìròyìn Rere Paná Ìròyìn Burúkú

    • • Òfófó (Àìsáyà 52:7)

    • • Ẹ̀rí Ọkàn Tó Ń Dani Láàmú (1 Jòhánù 1:7, 9)

    • • Àwọn Nǹkan Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Láyé (Mátíù 24:14)

    • • Ìrẹ̀wẹ̀sì (Mátíù 11:28-30)

  • 2:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: “Ara Mi Wà Lọ́nà Láti Kéde Ìhìn Rere”

    • • Kì í Ṣe Iṣẹ́ Àwọn Àpọ́sítẹ́lì Nìkan (Róòmù 1:15; 1 Tẹsalóníkà 1:8)

    • • Ara Ìjọsìn Wa Ni (Róòmù 1:9)

    • • Rí I Pé O Ní Àwọn Nǹkan Tó Yẹ (Éfésù 6:15)

  • 3:15 FÍDÍÒ: “Bí Ìhìn Rere Náà Ṣe Ń So Èso, Tó sì Ń Gbilẹ̀ ní Gbogbo Ayé” (Kólósè 1:6)

  • 3:40 Orin 35 àti Ìfilọ̀

  • 3:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Wàásù Ìhìn Rere

    • • Níbikíbi Tó O Bá Wà (2 Tímótì 4:5)

    • • Níbikíbi Tí Ẹ̀mí Ọlọ́run Bá Darí Ẹ Sí (Ìṣe 16:6-10)

  • 4:15 Kí Lo Máa Ṣe “Nítorí Ìhìn Rere”? (1 Kọ́ríńtì 9:23; Àìsáyà 6:8)

  • 4:50 Orin 21 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́