Sunday
“Tí ẹ bá ní ìgbàgbọ́ . . . ,ó máa ṣẹlẹ̀”—Mátíù 21:21
ÀÁRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 137 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Obìnrin Tí Ìgbàgbọ́ Wọn Lágbára!
• Sérà (Hébérù 11:11, 12)
• Ráhábù (Hébérù 11:31)
• Hánà (1 Sámúẹ́lì 1:10, 11)
• Ọmọbìnrin Ísírẹ́lì Tí Wọ́n Mú Lẹ́rú (2 Ọba 5:1-3)
• Màríà Ìyá Jésù (Lúùkù 1:28-33, 38)
• Obìnrin Ará Foníṣíà (Mátíù 15:28)
• Màtá (Jòhánù 11:21-24)
• Àwọn Àpẹẹrẹ Òde Òní (Sáàmù 37:25; 119:97, 98)
11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀
11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ẹ “Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ìhìn Rere” (Máàkù 1:14, 15; Mátíù 9:35; Lúùkù 8:1)
11:45 Orin 22 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 126
1:50 FÍDÍÒ: Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kejì (Dáníẹ́lì 5:1–6:28; 10:1–12:13)
2:40 Orin 150 àti Ìfilọ̀
2:45 Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Sọ Ẹ́ Di Alágbára! (Dáníẹ́lì 10:18, 19; Róòmù 4:18-21)
3:45 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí