Sunday
“Kí Ọlọ́run tó ń fúnni ní ìrètí fi gbogbo ayọ̀ àti àlàáfíà kún inú yín”—Róòmù 15:13
ÀÁRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 101 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Wọ́n Ṣe Ohun Tó Jẹ́ Kí Àlàáfíà Wà
• Jósẹ́fù Àtàwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ (Gálátíà 6:7, 8; Éfésù 4:32)
• Àwọn Ará Gíbíónì (Éfésù 5:17)
• Gídíónì (Àwọn Onídàájọ́ 8:2, 3)
• Ábígẹ́lì (1 Sámúẹ́lì 25:27-31)
• Méfíbóṣétì (2 Sámúẹ́lì 19:25-28)
• Pọ́ọ̀lù àti Bánábà (Ìṣe 15:36-39)
• Àwọn Àpẹẹrẹ Òde Òní (1 Pétérù 2:17)
11:05 Orin 28 àti Ìfilọ̀
11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Kí Lo Lè Ṣe Láti Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run? (Jémíìsì 4:8; 1 Jòhánù 4:10)
11:45 Orin 147 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 23
1:50 FÍDÍÒ: Jèhófà Ń Darí Wa ní Ọ̀nà Àlàáfíà—Apá 2 (Àìsáyà 48:17, 18)
2:30 Orin 139 àti Ìfilọ̀
2:40 Ó Dájú Pé Àlàáfíà Máa Wà Láyé Àtọ̀run! (Róòmù 16:20; 1 Kọ́ríńtì 15:24-28; 1 Jòhánù 3:8)
3:40 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí