Sunday
“Jèhófà ń fi sùúrù dúró láti ṣojúure sí yín”—Àìsáyà 30:18
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 95 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Ní Sùúrù Bíi Tàwọn Wòlíì
• Èlíjà (Jémíìsì 5:10, 17, 18)
• Míkà (Míkà 7:7)
• Hósíà (Hósíà 3:1)
• Àìsáyà (Àìsáyà 7:3)
• Ìsíkíẹ́lì (Ìsíkíẹ́lì 2:3-5)
• Jeremáyà (Jeremáyà 15:16)
• Dáníẹ́lì (Dáníẹ́lì 9:22, 23)
11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀
11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ọlọ́run Máa Dáhùn Àdúrà Ẹ (Àìsáyà 64:4)
11:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
12:15 Orin 94 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 114
1:50 FÍDÍÒ: “Fi Ọ̀nà Rẹ Lé Jèhófà Lọ́wọ́”—Apá 2 (Sáàmù 37:5)
2:30 Orin 115 àti Ìfilọ̀
2:40 “Jèhófà Ń Fi Sùúrù Dúró Láti Ṣojúure sí Yín” (Àìsáyà 30:18-21; 60:17; 2 Àwọn Ọba 6:15-17; Éfésù 1:9, 10)
3:40 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí