Sunday
“Jẹ́ kí inú rẹ máa dùn jọjọ nínú Jèhófà, yóò sì fún ọ ní àwọn ohun tí ọkàn rẹ fẹ́”—Sáàmù 37:4
ÀÁRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 22 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: A Lè Láyọ̀ Bá A Tiẹ̀ Ń Dojú Kọ . . .
• Ìpọ́njú (Róòmù 5:3-5; 8:35, 37)
• Wàhálà (2 Kọ́ríńtì 4:8; 7:5)
• Inúnibíni (Mátíù 5:11, 12)
• Ebi (Fílípì 4:11-13)
• Ìhòòhò (1 Kọ́ríńtì 4:11, 16)
• Ewu (2 Kọ́ríńtì 1:8-11)
• Idà (2 Tímótì 4:6-8)
11:10 Orin 9 àti Ìfilọ̀
11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Báwo Lo Ṣe Lè Ní Ọrọ̀ Láìsí Ìrora? (Òwe 10:22; 1 Tímótì 6:9, 10; Ìfihàn 21:3-5)
11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
12:20 Orin 84 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:40 Fídíò Orin
1:50 Orin 62
1:55 FÍÌMÙ: Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”—Apá Kejì (Nehemáyà 8:1–13:30; Málákì 1:6–3:18)
2:40 Orin 71 àti Ìfilọ̀
2:50 “Jẹ́ Kí Inú Rẹ Máa Dùn Jọjọ Nínú Jèhófà”!(Sáàmù 16:8, 9, 11; 37:4)
3:50 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí