ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm17 ojú ìwé 2-3
  • Friday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Friday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
CO-pgm17 ojú ìwé 2-3
Àwòrán tó jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a máa gbádùn ní òwúrọ̀ ọjọ́ Friday nínú ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2017.

Friday

“Ẹ má ṣe jẹ́ kí a juwọ́ sílẹ̀ ní ṣíṣe ohun tí ó dára lọ́pọ̀lọpọ̀” ​—⁠GÁLÁTÍÀ 6:9

ÒWÚRỌ̀

  • 8:20 [8:20]* Fídíò Orin

  • 8:30 [8:30] Orin 77 àti Àdúrà

  • 8:40 [8:40] Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: A Ò Gbọ́dọ̀ Sọ̀rètí Nù Lákòókò Tá A Wà Yìí! (Ìṣípayá 12:⁠12)

  • 9:15 [9:15] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Wàásù Nìṣó “Láìdábọ̀”

    • Lọ́nà Àìjẹ́-Bí-Àṣà (Ìṣe 5:42; Oníwàásù 11:⁠6)

    • Láti Ilé-Dé-Ilé (Ìṣe 20:⁠20)

    • Níbi Térò Pọ̀ Sí (Ìṣe 17:⁠17)

    • Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn (Róòmù 1:​14-16; 1 Kọ́ríńtì 3:⁠6)

  • 10:05 [10:05] Orin 76 àti Ìfilọ̀

  • 10:15 [10:15] BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Jèhófà Máa Ń Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Sílẹ̀ (Ẹ́kísódù 3:​1-22; 4:​1-9; 5:​1-9; 6:​1-8; 7:​1-7; 14:​5-10, 13-31; 15:​1-21)

  • [10:45] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí

    • “Ní Ìtẹ́lọ́rùn Pẹ̀lú Àwọn Nǹkan Ìsinsìnyí” (Hébérù 13:5; Sáàmù 127:​1, 2)

    • Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ “Ohun Tí Ó Jẹ́ Ibi” (Róòmù 16:19; Sáàmù 127:⁠3)

    • Ẹ Tọ́ Àwọn Ọmọ Yín ‘Ní Ọ̀nà Tí Wọn Yóò Tọ̀’ (Òwe 22:​3, 6; Sáàmù 127:​4, 5)

  • 10:45 [11:30] Jèhófà Ni Àpẹẹrẹ Tó Dáa Jù Lọ Tó Bá Dọ̀rọ̀ Ìfaradà (Róòmù 8:​22, 23; 15:13; Jákọ́bù 1:​2-4)

  • 11:15 [12:00] Orin 115 àti Àkókò Ìsinmi

Àwòrán tó jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a máa gbádùn ní ọ̀sán ọjọ́ Friday nínú ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún 2017.

Ọ̀SÁN

  • 12:25 [1:00] Fídíò Orin

  • 12:35 [1:10] Orin 128

  • 12:40 [1:15] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: À Ń Fara Dà Á Láìka . . .

    • Ìwà Ìrẹ́jẹ (Mátíù 5:​38, 39)

    • Ara Tó Ti Ń Dara Àgbà (Aísáyà 46:4; Júúdà 20, 21)

    • Àìpé Tiwa Fúnra Wa (Róòmù 7:​21-25)

    • Ìbáwí Tí Kò Bára Dé (Gálátíà 2:​11-14; Hébérù 12:​5, 6, 10, 11)

    • Àìsàn Ọlọ́jọ́ Pípẹ́ (Sáàmù 41:⁠3)

    • Ikú Èèyàn Wa (Sáàmù 34:⁠18)

    • Inúnibíni (Ìṣípayá 1:⁠9)

  • 1:55 [2:30] Orin 136 àti Ìfilọ̀

  • 2:05 [2:40] ÀWÒKẸ́KỌ̀Ọ́: Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì​—⁠Apá Kìíní (Lúùkù 17:​28-33)

  • 2:35 [3:10] ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Sapá Láti Ní Àwọn Ànímọ́ Tó Máa Jẹ́ Kó O Lè Fara Dà Á

    • Ìgbàgbọ́ (Hébérù 11:⁠1)

    • Ìwà Funfun (Fílípì 4:​8, 9)

    • Ìmọ̀ (Òwe 2:​10, 11)

    • Ìkóra-Ẹni-Níjàánu (Gálátíà 5:​22, 23)

  • 3:15 [3:50] Bí A Ò Ṣe Ní “Kùnà Lọ́nàkọnà Láé” (2 Pétérù 1:​5-10; Aísáyà 40:31; 2 Kọ́ríńtì 4:​7-9, 16)

  • 3:50 [4:25] Orin 3 àti Àdúrà Ìparí

* Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “gbálùúmọ́”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́