ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm20 ojú ìwé 4-5
  • Saturday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Saturday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
CO-pgm20 ojú ìwé 4-5
Àwòrán: 1. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà wà lóde ẹ̀rí, inú wọn sì ń dùn. Arọ ni ọ̀kan nínú wọn, wọ́n sì ń tì í lórí kẹ̀kẹ́ arọ. 2. Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ń bá ọkùnrin kan tó jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ Amish sọ̀rọ̀ nípa Bíbélì. 3. Nehemáyà.

Saturday

“Ẹ máa fi orúkọ mímọ́ rẹ̀ yangàn. Kí ọkàn àwọn tó ń wá Jèhófà máa yọ̀”​—Sáàmù 105:3

ÀÁRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 53 àti Àdúrà

  • 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá

    • • Máa Lo Ìbéèrè (Jémíìsì 1:19)

    • • Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní (Hébérù 4:12)

    • • Máa Fi Àpèjúwe Ṣàlàyé Kókó Pàtàkì (Mátíù 13:​34, 35)

    • • Máa Lo Ìtara Tó O Bá Ń Kọ́ni (Róòmù 12:11)

    • • Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò (1 Tẹsalóníkà 2:​7, 8)

    • • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn (Òwe 3:1)

  • 10:50 Orin 58 àti Ìfilọ̀

  • 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè

    • • Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí (1 Kọ́ríńtì 3:9; 2 Tímótì 3:16, 17)

    • • Àwọn Ará (Róòmù 16:3, 4; 1 Pétérù 5:9)

    • • Àdúrà (Sáàmù 127:1)

  • 11:45 ÌRÌBỌMI: Bí Ìrìbọmi Ṣe Máa Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Láyọ̀ (Òwe 11:24; Ìfihàn 4:11)

  • 12:15 Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀SÁN

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 76

  • 1:50 Bí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Ṣe Ń Fún Àwọn Ará Wa Láyọ̀ ní . . .

    • • Áfíríkà

    • • Éṣíà

    • • Yúróòpù

    • • Amẹ́ríkà ti Àríwá

    • • Oceania

    • • Amẹ́ríkà ti Gúúsù

  • 2:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti . . .

    • • Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́ (Mátíù 5:3; Jòhánù 13:17)

    • • Máa Wá Sípàdé (Sáàmù 65:4)

    • • Yẹra fún Ẹgbẹ́ Búburú (Òwe 13:20)

    • • Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́ (Éfésù 4:​22-24)

    • • Ní Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà (1 Jòhánù 4:​8, 19)

  • 3:30 Orin 110 àti Ìfilọ̀

  • 3:40 FÍÌMÙ: Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”​—Apá Kìíní (Nehemáyà 1:1–6:19)

  • 4:15 Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn ti Ìsinsìnyí Ń Múra Wa Sílẹ̀ De ti Ayé Tuntun (Àìsáyà 11:9; Ìṣe 24:15)

  • 4:50 Orin 140 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́