ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm21 ojú ìwé 4-5
  • Saturday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Saturday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
CO-pgm21 ojú ìwé 4-5
Àwòrán: 1. Arábìnrin kan ń bá ọmọ rẹ̀ ọkùnrin àti obìnrin sọ̀rọ̀. 2. Arábìnrin méjì ń wàásù ní ìgbèríko kan nílẹ̀ Éṣíà. 3. Dáníẹ́lì àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́ta tí wọ́n jọ jẹ́ Hébérù dúró níwájú ọba Bábílónì.

Saturday

“Ẹ máa jà fitafita torí ìgbàgbọ́”​—Júùdù 3

ÀÁRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 57 àti Àdúrà

  • 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Rántí Pé Àwọn Aláìgbàgbọ́ Lè Di Onígbàgbọ́!

    • • Àwọn Ará Ìlú Nínéfè (Jónà 3:5)

    • • Àwọn Àbúrò Jésù (1 Kọ́ríńtì 15:7)

    • • Àwọn Gbajúmọ̀ (Fílípì 3:7, 8)

    • • Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan (Róòmù 10:13-15; 1 Kọ́ríńtì 9:22)

  • 10:30 Fi Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Lágbára (Jòhánù 17:3)

  • 10:50 Orin 67 àti Ìfilọ̀

  • 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ìgbàgbọ́ Ń Mú Kí Wọ́n Ja Àjàṣẹ́gun

    • • Àwọn Tí Ọkọ Tàbí Aya Wọn Kì Í Ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà (Fílípì 3:17)

    • • Àwọn Tí Òbí Kan Ṣoṣo Tọ́ (2 Tímótì 1:5)

    • • Àwọn Tí Kò Ní Ọkọ Tàbí Aya (1 Kọ́ríńtì 12:25)

  • 11:45 ÌRÌBỌMI: Ẹni Tó Bá Ń Ní Ìgbàgbọ́ Máa Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun! (Mátíù 17:20; Jòhánù 3:16; Hébérù 11:6)

  • 12:15 Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀SÁN

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 24

  • 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Hàn Pé Àwọn Nígbàgbọ́ ní . . .

    • • Áfíríkà

    • • Amẹ́ríkà ti Àríwá

    • • Éṣíà

    • • Oceania

    • • Yúróòpù

    • • Amẹ́ríkà ti Gúúsù

  • 2:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Mú Kó O Ṣe Púpọ̀ Sí I

    • • Kọ́ Èdè Míì (1 Kọ́ríńtì 16:9)

    • • Lọ Síbi Tí Àìní Pọ̀ Sí (Hébérù 11:8-10)

    • • Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere (1 Kọ́ríńtì 4:17)

    • • Máa Ṣèrànwọ́ Níbi Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ètò Ọlọ́run (Nehemáyà 1:2, 3; 2:5)

    • • Máa “Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀” fún Iṣẹ́ Jèhófà (1 Kọ́ríńtì 16:2)

  • 3:15 Orin 84 àti Ìfilọ̀

  • 3:20 FÍDÍÒ: Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀​—Apá Kìíní (Dáníẹ́lì 1:1–2:49; 4:​1-33)

  • 4:20 “Ẹ Máa Jà Fitafita Torí Ìgbàgbọ́”! (Júùdù 3; Òwe 14:15; Róòmù 16:17)

  • 4:55 Orin 38 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́