ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm21 ojú ìwé 6-7
  • Sunday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sunday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2023
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2022
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
CO-pgm21 ojú ìwé 6-7
Àwòrán: 1. Ọmọbìnrin Ísírẹ́lì tí wọ́n mú lẹ́rú ń bá ìyàwó ọ̀gá rẹ̀ sọ̀rọ̀. 2. Ella Toom nígbà tó ṣì kéré. 3. Matsui Ishii nígbà tó ṣì kéré. 4. Dáníẹ́lì kọjú síta látojú fèrèsé, ó ń gbàdúrà.

Sunday

“Tí ẹ bá ní ìgbàgbọ́ . . . ,ó máa ṣẹlẹ̀”​—Mátíù 21:21

ÀÁRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 137 àti Àdúrà

  • 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Obìnrin Tí Ìgbàgbọ́ Wọn Lágbára!

    • • Sérà (Hébérù 11:11, 12)

    • • Ráhábù (Hébérù 11:31)

    • • Hánà (1 Sámúẹ́lì 1:10, 11)

    • • Ọmọbìnrin Ísírẹ́lì Tí Wọ́n Mú Lẹ́rú (2 Ọba 5:1-3)

    • • Màríà Ìyá Jésù (Lúùkù 1:28-33, 38)

    • • Obìnrin Ará Foníṣíà (Mátíù 15:28)

    • • Màtá (Jòhánù 11:21-24)

    • • Àwọn Àpẹẹrẹ Òde Òní (Sáàmù 37:25; 119:97, 98)

  • 11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ẹ “Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ìhìn Rere” (Máàkù 1:14, 15; Mátíù 9:35; Lúùkù 8:1)

  • 11:45 Orin 22 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀SÁN

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 126

  • 1:50 FÍDÍÒ: Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀​—Apá Kejì (Dáníẹ́lì 5:1–6:28; 10:1–12:13)

  • 2:40 Orin 150 àti Ìfilọ̀

  • 2:45 Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Sọ Ẹ́ Di Alágbára! (Dáníẹ́lì 10:18, 19; Róòmù 4:18-21)

  • 3:45 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́