ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm19 ojú ìwé 4-5
  • Saturday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Saturday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2022
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
CO-pgm19 ojú ìwé 4-5
Ìdílé kan di ara wọn lọ́wọ́ mú, wọ́n sì ń sáré létíkun tayọ̀tayọ̀

Saturday

‘Ẹ MÁA RÌN NÍNÚ ÌFẸ́’​—ÉFÉSÙ 5:2

ÒWÚRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 85 àti Àdúrà

  • 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn

    • Tó Ń Mú Ipò Iwájú (1 Tẹsalóníkà 5:12, 13)

    • Opó Àtàwọn Ọmọ Aláìníbaba (Jémíìsì 1:27)

    • Àgbàlagbà (Léfítíkù 19:32)

    • Òjíṣẹ́ Alákòókò Kíkún (1 Tẹsalóníkà 1:3)

    • Àjèjì (Léfítíkù 19:34; Róòmù 15:7)

  • 10:50 Orin 58 àti Ìfilọ̀

  • 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù

    • Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run (1 Jòhánù 5:3)

    • “Nífẹ̀ẹ́ Ọmọnìkejì Rẹ Bí Ara Rẹ” (Mátíù 22:39)

    • Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Jèhófà (Sáàmù 119:97; Mátíù 13:52)

  • 11:45 ÌRÌBỌMI: Kọ́ Bó O Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Lára Jésù (Mátíù 11:28-30)

  • 12:15 Orin 52 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀SÁN

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 84

  • 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn ní . . .

    • Áfíríkà (Jẹ́nẹ́sísì 16:13)

    • Éṣíà (Ìṣe 2:44)

    • Yúróòpù (Jòhánù 4:35)

    • Amẹ́ríkà Ti Àríwá (1 Kọ́ríńtì 9:22)

    • Oceania (Sáàmù 35:18)

    • Amẹ́ríkà Ti Gúúsù (Ìṣe 1:8)

  • 2:55 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Nínú Ìdílé

    • Nífẹ̀ẹ́ Ìyàwó Rẹ (Éfésù 5:28, 29)

    • Nífẹ̀ẹ́ Ọkọ Rẹ (Éfésù 5:33; 1 Pétérù 3:1-6)

    • Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ọmọ Rẹ (Títù 2:4)

  • 3:35 Orin 35 àti Ìfilọ̀

  • 3:45 FÍÌMÙ: Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kìíní (2 Kíróníkà 33:10-24; 34:1, 2)

  • 4:15 Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Máa Fi Ìfẹ́ Hàn (2 Tímótì 3:14, 15)

  • 4:50 Orin 134 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́