Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìhìn Rere Tì Ẹ́ Lójú
Àárọ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 67 àti Àdúrà
10:00 Kí Nìdí Tí ‘Ìhìn Rere Ò Fi Tì Wá lójú?’
10:15 Máa Fìgboyà Sọ Ohun Tó O Gbà Gbọ́
10:30 Jẹ́ “Òṣìṣẹ́ Tí Kò Ní Ohunkóhun Tó Máa Tì Í Lójú”
10:55 Orin 73 àti Ìfilọ̀
11:05 Bá A Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Ní Ẹ̀mí Agbára, Ìfẹ́ àti Àròjinlẹ̀
11:35 Ìrìbọmi: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere”
12:05 Orin 75