ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 4
  • Jóòbù Kò Fàyè Gba Èrò Òdì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jóòbù Kò Fàyè Gba Èrò Òdì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jóòbù Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • “Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Ta Ni Jóòbù?
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • “Mi Ò Ní Fi Ìwà Títọ́ Mi Sílẹ̀!”
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 21-27

Jóòbù Kò Fàyè Gba Èrò Òdì

Jóòbù fi ọwọ́ bo etí rẹ̀

Lóde òní, Sátánì máa ń pa oríṣiríṣi irọ́ mọ́ Ọlọ́run kó lè kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà. Wo ìyàtọ̀ tó wà nínú àwọn irọ́ tí Sátánì ń pa mọ́ Jèhófà àti bí ọ̀rọ̀ wa ṣe rí lára Jèhófà gan-an nínú ìwé Jóòbù. Kọ àwọn ẹsẹ Bíbélì míì tó jẹ́ kó o gbà pé Jèhófà bìkítà nípa rẹ sórí ìlà tó wà nísàlẹ̀ yìí.

ÀWỌN IRỌ́ TÍ SÁTÁNÌ Ń PA

BÍ Ọ̀RỌ̀ WA ṢE RÍ LÁRA JÈHÓFÀ GAN-AN

Ọlọ́run rorò débi pé kò sóhun táwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣe tó dára lójú rẹ̀. Kò sí ẹ̀dá kankan tó lè tẹ́ ẹ lọ́rùn (Job 4:18; 25:5)

Jèhófà mọyì àwọn ìsapá wa (Job 36:5)

Èèyàn ò wúlò fún Ọlọ́run (Job 22:2)

Inú Jèhófà máa ń dùn sí iṣẹ́ ìsìn tá a fi tọkàntọkàn ṣe, ó sì ń bù kún wa (Job 33:26; 36:11)

Jíjẹ́ tí o jẹ́ olódodo kò já mọ́ nǹkan kan lójú Ọlọ́run (Job 22:3)

Ojú Jèhófà kì í kúrò lára olódodo (Job 36:7)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́