ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 8
  • Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso!

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso!
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Kí Ìjọba Rẹ Dé”—Àdúrà Tí Àìmọye Èèyàn Ń Gbà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ẹ Máa Bá A Nìṣó Gẹ́gẹ́ Bí Ọmọ Ìjọba Ọlọ́run!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ṣé inú Ọkàn Rẹ ni Ìjọba Ọlọ́run Wà?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 8

ÌGBÉ AYÉ KRISTẸNI

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso!

Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ tí wọ́n so ẹ̀rọ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ mọ́, Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fi káàdì fífẹ̀ tí wọ́n kọ nǹkan sí polongo àsọyé

Àwọn tó bá fẹ́ di ọmọ abẹ́ Ìjọba Ọlọ́run gbọ́dọ̀ kọ́ nípa Ìjọba náà àtàwọn ohun tó ti gbé ṣe. Kí nìdí? Ìdí ni pé ó máa jẹ́ kí wọ́n rí i pé Ìjọba Ọlọ́run ti ń ṣàkóso, á sì tún jẹ́ kí wọ́n lè wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run fún àwọn èèyàn. (Sm 45:1; 49:⁠3) Ẹ wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso, kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  1. Kí nìdí tá a fi lè sọ pé ìbùkún ní “Àwòkẹ́kọ̀ọ́ Onífọ́tò Nípa Ìṣẹ̀dá” jẹ́ fún àwọn tó wò ó?

  2. Báwo la ṣe lo rédíò láti wàásù ìhìn rere?

  3. Àwọn ọ̀nà míì wo la gbà wàásù ìhìn rere, kí ló sì yọrí sí?

  4. Báwo la ṣe ń mú kí ìdálẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣẹ́ ìwàásù sunwọ̀n sí i?

  5. Ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó gbéṣẹ́ wo làwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì ń gbà?

  6. Báwo ni Jèhófà ṣe ń fi àpéjọ àgbègbè dá àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́?

  7. Kí ló jẹ́ kó dá ọ lójú pé Ìjọba Ọlọ́run ti ń ṣàkóso?

  8. Báwo la ṣe lè ti Ìjọba Ọlọ́run lẹ́yìn?

Ìwé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso! la máa bẹ̀rẹ̀ sí í kà ní Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ bẹ̀rẹ̀ láti ọ̀sẹ̀ September 19, 2016

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́