ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 6
  • “Ọlọ́run Ni Olùrànlọ́wọ́ Mi”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọlọ́run Ni Olùrànlọ́wọ́ Mi”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ju Ẹrù Ìnira Rẹ Sọ́dọ̀ Jèhófà”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Jèhófà Ń Ran Àwọn Tó Gbẹ́kẹ̀ Lé E Lọ́wọ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2004
  • Jẹ́ Kí Ọlọ́run Máa Ṣamọ̀nà Rẹ Nínú Ohun Gbogbo
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ìgbọ́kànlé Kíkún Nínú Jèhófà Ń Mú Ká Ní Ìgboyà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 6

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Ọlọ́run Ni Olùrànlọ́wọ́ Mi”

Ìwé Sáàmù 52-59 jẹ́ ká mọ bí nǹkan ṣe rí lára Dáfídì láwọn ìgbà tó ní ìṣòro. Àmọ́, ó ṣì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà láwọn àkókò tí nǹkan kò rọrùn fún un yẹn. (Sm 54:4; 55:22) Ó tún yin Jèhófà nítorí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. (Sm 56:10) Ǹjẹ́ àwa náà ń sapá láti ní irú ìgbàgbọ́ àti ìgbẹ́kẹ̀lé bẹ́ẹ̀ nínú Ọlọ́run? Ṣé a máa ń wá ìtọ́sọ́nà nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tá a bá ní ìṣòro? (Owe 2:⁠6) Ẹsẹ Bíbélì wo ló ràn ọ́ lọ́wọ́ nígbà tó o . . .

  • ní ìrẹ̀wẹ̀sì tàbí soríkọ́?

  • ṣàìsàn?

  • tí ẹnì kan ṣe ohun tó dùn ọ́?

  • tí wọ́n ṣe inúnibíni sí ọ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́