ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 5
  • Jèhófà Máa Ń Rántí Pé Ekuru Ni Wá

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ń Rántí Pé Ekuru Ni Wá
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ó Rántí Pé “Ekuru Ni Wá”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • “Fi Ìbùkún fún Jèhófà, Ìwọ Ọkàn Mi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Burú Jáì Jini?
    Jí!—2008
  • Ọlọ́run Tó “Ṣe Tán Láti Dárí Jini”
    Sún Mọ́ Jèhófà
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 102-105

Jèhófà Máa Ń Rántí Pé Ekuru Ni Wá

Ọkùnrin kan bu ekuru sí ọwọ́ rẹ̀, ó wà ń ronú lórí bí ojú ọ̀run ṣe kún fún ìràwọ̀ àti oòrùn tó àti bí bàbá kan ṣe ń ṣaájò ọmọ rẹ̀

Dáfídì lo ọ̀rọ̀ àfiwé láti fi ṣàpèjúwe àánú Jèhófà.

  • Ojú ọ̀run tó kún fún ìràwọ̀

    103:11

    Bó ṣe jẹ́ pé ó kọjá òye ẹ̀dá láti mọ́ bí ojú ọ̀run tó kún fún ìràwọ̀ ṣe jìnnà tó sí ilẹ̀ ayé, bẹ́ẹ̀ la ò ṣe lè díwọ̀n bí inú rere onífẹ̀ẹ́ Jèhófà ṣe pọ̀ tó

  • Oòrùn

    103:12

    Bí a ò ṣe lè mọ bí yíyọ oòrùn ṣe jìnnà sí wíwọ̀ oòrùn tó, bẹ́ẹ̀ ló ṣe jẹ́ pé tí Jèhófà bá ti dárí jí wà, ó máa ń mú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnà réré sí wa

  • Bàbá kan ń ṣaájò ọmọ rẹ̀

    103:13

    Bí baba kan ṣe máa ń ṣaájò ọmọ rẹ̀ tó fara pa, bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ṣe máa ń fi àánú hàn sí àwọn tí wọ́n bá ronú pìwà dà, àmọ́ tí ẹ̀ṣẹ̀ wọn ń kó ẹ̀dùn ọkàn bá wọn

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́