ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 7
  • “Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Máa Dúpẹ́ Ohun Gbogbo”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Ṣé Wàá Lo Àǹfààní Yìí?
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Máa Dúpẹ́ Oore
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ẹ̀mí Ìmoore
    Jí!—2016
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 110-118

“Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”

Onísáàmù náà ń fi háàpù kọrin
Wọ́n so okùn mọ́ ẹnì kan lọ́wọ́

Onísáàmù náà mọ rírì Jèhófà gan-an ni, ìdí sì ni pé Jèhófà kó o yọ nínú “ìjàrá ikú.” (Sm 116:⁠3) Láti fi hàn pé ó mọ rírì Jèhófà, ó pinnu pé òun máa mú gbogbo ìlérí òun ṣẹ̀ àti pé gbogbo ohun tí Jèhófà bá ní kí oun ṣe lòun máa ṣe.

Kí nìdí tó fi yẹ kí n mọ rírì Jèhófà lọ́sẹ̀ yìí?

Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo mọ rírì Jèhófà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́