ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 August ojú ìwé 2
  • Máa Dúpẹ́ Oore

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Dúpẹ́ Oore
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dúpẹ́ Oore?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ṣé Wàá Lo Àǹfààní Yìí?
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Máa Moore
    Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé
  • “Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 August ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 17-18

Máa Dúpẹ́ Oore

17:​11-18

Ọkùnrin adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá ló bẹ̀bẹ̀ pé kí Jésù ṣàánú àwọn, Jésù sì wo gbogbo wọn sàn, àmọ́ ọ̀kan ṣoṣo nínú wọn ló pa dà wá dúpẹ́ lọ́wọ́ Jésù

Kí ni ìṣẹ̀lẹ̀ yìí kọ́ wa nípa kéèyàn máa dúpẹ́ oore?

  • Kì í ṣe pé ká kàn moore nìkan, a tún gbọ́dọ̀ máa dúpẹ́ oore

  • Tá a bá ń dúpẹ́ oore látọkàn wá, ó fi hàn pé lóòótọ́ la ní irú ìfẹ́ tó yẹ kí Kristẹni ní àti pé a níwà ọmọlúwàbí

  • Àwọn tó ń fẹ́ ṣe ohun tí Kristi fẹ́ gbọ́dọ̀ máa fìfẹ́ hàn sí gbogbo èèyàn, kí wọ́n sì mọyì wọn, láìka orílẹ̀-èdè, ẹ̀yà tàbí ẹ̀sìn wọn sí

Ṣé mo máa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn tó bá ṣe mí lóore?

Ìgbà wo ni mo kọ̀wé láti dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹnì kan kẹ́yìn?

Arábìnrin kan ń kọ ọ̀rọ̀ ìdúpẹ́ sínú ìwé kékeré kan
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́