ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 September ojú ìwé 6
  • “Jèhófà Tóbi, Ó sì Yẹ fún Ìyìn Gidigidi”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Jèhófà Tóbi, Ó sì Yẹ fún Ìyìn Gidigidi”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwámáridìí ni Títóbi Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Inú-rere-onífẹ̀ẹ́ Jèhófà Mà Pọ̀ O!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Ẹ Yin Jèhófà, Ọlọ́run Wa!
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ẹ Yin Jèhófà Ọlọ́run Wa!
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 September ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 142-150

“Jèhófà Tóbi, Ó sì Yẹ fún Ìyìn Gidigidi”

145:1-5

Àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run

Dáfídì rí i pé títóbi Jèhófà kò ní ààlà, ìyẹn sì mú kó sọ pé òun á máa yin Jèhófà títí ayé

145:10-12

Bíi ti Dáfídì, gbogbo ìgbà làwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Jèhófà máa ń sọ̀rọ̀ nípa agbára ńlá rẹ̀

Ìdílé kan ń wo àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì

145:14

Ẹnì kan di ẹni tó fẹ́ ràn án lọ́wọ́ mú

Ó dá Dáfídì lójú pé ó máa ń wu Jèhófà láti ṣìkẹ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti pé ó lágbára láti ṣe bẹ́ẹ̀

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́