ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 November ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ILÉ ÌṢỌ́
  • MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI
  • KÍ NÌDÍ TÓ FI YẸ KÓ O KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ?  (Fídíò)
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 November ojú ìwé 1
Arábìnrin méjì ń wàásù fún obìnrin kan lédè Tzotzil, nílùú Chiapas, lórílẹ̀-èdè Mẹ́síkò

Àwọn aṣáájú ọ̀nà ń wàásù ìhìn rere ní èdè Tzotzil, nílùú Chiapas, lórílẹ̀-èdè Mẹ́síkò

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

ILÉ ÌṢỌ́

Ilé Ìṣọ́ No. 6 2016 | Àwọn Wo Ló Ń Gbé Ní Ọ̀run?

Béèrè ìbéèrè: Tí ẹnì kan bá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé báwo ni ọ̀run ṣe rí, kí lo máa sọ?

Ka Bíbélì: Jo 8:23

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí ṣàlàyé ohun tí Jésù àti Bàbá rẹ̀ sọ nípa ọ̀run.

MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI

Bíbélì tí wọ́n ṣí dání

Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ o gbà pé ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lákòókò wa yìí ni asọtẹ́lẹ̀ inú ẹsẹ Bíbélì yìí dá lé?

Ka Bíbélì: 2Ti 3:1-5

Òtítọ́: Níwọ̀n bí àwọn asọtẹ́lẹ̀ tí Bíbélì sọ nípa ọjọ́ ìkẹyìn ti ń ṣẹ báyìí, ó dá wa lójú pé àwọn àsọtẹ́lẹ̀ míì tó sọ pé nǹkan ṣì ń bọ̀ wá dáa náà máa ṣẹ.

KÍ NÌDÍ TÓ FI YẸ KÓ O KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ?  (Fídíò)

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (fídíò)

Ìnasẹ̀ ọ̀rọ̀: À ń fi fídíò yìí han àwọn èèyàn láti ṣàlàyé ibi tá a ti lè rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè pàtàkì ní ìgbésí ayé. [Jẹ́ kó wo fídíò náà.]

Fi ìwé lọni: Ìwé yìí sọ bí Ọlọ́run á ṣe yanjú gbogbo ìṣòro tó wà láyé yìí. [Fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni lọ̀ ọ́.]

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́