ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • JÍ!
  • MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI
  • KÍ NÌDÍ TÓ FI YẸ KÓ O KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ? (Fídíò)
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 1
Arábìnrin méjì ń kọ́ ẹnì kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Chile

Wọ́n ń kọ́ ẹnì kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Chile

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Jí! No. 6 2016 | Bá A Ṣe Lè Dènà Àrùn

Béèrè ìbéèrè: Gbogbo wa ló máa ń wù pé ká ní ìlera tó dáa. Kí lẹ rò pé a lè ṣe ká má báa máa ṣàìsàn ní gbogbo ìgbà?

Ka Bíbélì: Owe 22:3

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Jí! yìí sọ onírúurú nǹkan tá a lè ṣe tí a ò fi ní máa ṣàìsàn ní gbogbo ìgbà.

MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI

Wọ́n ṣí Bíbélì sílẹ̀

Béèrè ìbéèrè: Ṣé Ọlọ́run ló ń fa ìyà tó ń jẹ àwa èèyàn, àbí nǹkan míì ló ń fà á?

Ka Bíbélì: Job 34:10

Òtítọ́: Ọlọ́run kọ́ ló ń fa ìyà tó ń jẹ àwa èèyàn. Kàkà bẹ́ẹ̀, Èṣù ló ń fa ìyà tó ń jẹ wá, ó sì tún lè jẹ́ àfọwọ́fà àwọn èèyàn, tàbí kéèyàn ṣe kòńgẹ́ aburú. Tá a bá ń jìyà, Ọlọ́run wà níbẹ̀ fún wa láti ràn wá lọ́wọ́, torí pé ó bìkítà fún wa.

KÍ NÌDÍ TÓ FI YẸ KÓ O KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ? (Fídíò)

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (fídíò)

Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ ẹ rò pé Ọlọ́run ló ń darí ayé yìí? [Jẹ́ kó fèsì.] Ohun tí Bíbélì sọ lórí kókó yìí lè yà yín lẹ́nu. Fídíò kékeré yìí sọ díẹ̀ lára wọn. [Jẹ́ kó wo fídíò náà.]

Fi ìwé lọni: Orí 11 nínú ìwé yìí ṣàlàyé ìdí tí Ọlọ́run kò tíì fi mú ìyà tó ń jẹ wá kúrò, ó sì tún ṣàlàyé ohun tó máa ṣe nípa rẹ̀. [Fún un ní ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni.]

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́