ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 November ojú ìwé 2
  • ‘Ẹni Mímọ̀ Ni Ọkọ Rẹ̀ Jẹ́ Ní Àwọn Ẹnubodè’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Ẹni Mímọ̀ Ni Ọkọ Rẹ̀ Jẹ́ Ní Àwọn Ẹnubodè’
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Látọ̀dọ̀ Ìyá Kan
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Bíbélì Sọ Ohun Tí Ìyàwó Tó Dáńgájíá Máa Ń Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Fún Àwọn Tọkọtaya
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Ki Ni Itẹriba Ninu Igbeyawo Tumọsi?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 November ojú ìwé 2

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

‘Ẹni Mímọ̀ Ni Ọkọ Rẹ̀ Jẹ́ Ní Àwọn Ẹnubodè’

Tí ọkùnrin kan bá ní aya tó dáńgájíá, ó máa ń hàn nínú ìrísí ọkùnrin náà. Nígbà ayé Lémúẹ́lì Ọba, “ẹni mímọ̀” ni ọkọ obìnrin tó dáńgájíá máa ń jẹ́ “ní àwọn ẹnubodè.” (Owe 31:23) Lóde òní, àwọn ọkùnrin tá a bọ̀wọ̀ fún ló máa ń sìn nípò alàgbà àti ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́. Tí wọ́n bá ti níyàwó, ìwà rere àti ìtìlẹ́yìn ìyàwó wọn ló máa jẹ́ kí wọ́n kúnjú ìwọ̀n fún àǹfààní yìí. (1Ti 3:4, 11) Àwọn ọkùnrin tó nírú ìyàwó bẹ́ẹ̀ máa ń mọyì ìyàwó wọn gan-an, àwọn ará ìjọ náà sì máa ń mọyì wọn.

Ìyàwó kan ń sọ̀rọ̀ tútù fún ọkọ rẹ̀, ó ń bojú tó àwọn ọmọ nígbà tí ọkọ rẹ̀ ń ṣiṣẹ́ ìjọ, ó lọ ra oúnjẹ

Ìyàwó tó dáńgájíá máa ń jẹ́ kí ọkọ rẹ̀ ní àǹfààní iṣẹ́ ìsìn nípa ṣíṣe àwọn nǹkan yìí . . .

  • ó máa ń sọ̀rọ̀ rere láti fún ọkọ rẹ̀ níṣìírí.​—Owe 31:26

  • ó máa ń ti ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn tinútinú kí ó lè bójú tó àwọn iṣẹ́ ìjọ.​—1Tẹ 2:7, 8

  • ó máa ń gbé ìgbé ayé ṣe bí o ti mọ.​—1Ti 6:8

  • kì í béèrè àwọn àṣírí ìjọ lọ́wọ́ ọkọ rẹ̀.​—1Ti 2:11, 12; 1Pe 4:15

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́