ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 18-20
Tí Jèhófà Bá Ti Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Jini, Ṣé Ó Máa Ń Gbàgbé Rẹ̀?
Bí Jèhófà bá ti dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji ẹnì kan, kò ní fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ náà jẹ ẹ́ lọ́jọ́ iwájú.
Àwọn àpẹẹrẹ inú Bíbélì yìí fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé Jèhófà ń dárí jini.
Ọba Dáfídì
Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá?
Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í?
Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?
Ọba Mánásè
Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá?
Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í?
Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?
Àpọ́sítélì Pétérù
Ẹ̀ṣẹ̀ wo ló dá?
Kí nìdí tí Jèhófà fi dárí jì í?
Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ti dárí jì í?