ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 October ojú ìwé 4
  • Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọba Méjì wọ Gídígbò
    Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì
  • Ta ni Yóò Ṣàkóso Ayé?
    Kíyè sí Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 October ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 10-12

Jèhófà Mọ Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọba

11:2

Ọba mẹ́rin máa dìde ní ilẹ̀ Páṣíà. Ọba kẹrin máa “gbé ohun gbogbo dìde lòdì sí ìjọba ilẹ̀ Gíríìsì.”

  1. Kírúsì Ńlá

  2. Kanbáísísì Kejì

  3. Dáríúsì Kìíní

  4. Sásítà Kìíní (tí àwọn èèyàn gbà gbọ́ pé òun ni Ọba Ahasuwérúsì tó fẹ́ Ẹ́sítérì)

11:3

Ọba kan máa dìde ní ilẹ̀ Gíríìsì, àkóso rẹ̀ sì máa dé ibi tó pọ̀ gan-an.

  • Alẹkisáńdà Ńlá

11:4

Àwọn ọ̀gágun Alẹkisáńdà mẹ́rin máa pín àkóso Ilẹ̀ Ọba Gíríìsì láàárín ara wọn.

  1. Kasáńdà

  2. Lisimákù

  3. Sẹ̀lẹ́úkọ́sì Kìíní

  4. Tọ́lẹ́mì Kìíní

Ìṣàkóso Ilẹ̀ Ọba Gírí ìkì pín sí ọwọ́ àwọn ọ̀gágun Alẹkisáńdà mẹ́rin
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́