ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 October ojú ìwé 8
  • ‘Àwọn Ọmọkùnrin Yín àti Àwọn Ọmọbìnrin Yín Yóò Máa Sọ Tẹ́lẹ̀’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Àwọn Ọmọkùnrin Yín àti Àwọn Ọmọbìnrin Yín Yóò Máa Sọ Tẹ́lẹ̀’
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣọra Fun Awọn Wolii Èké!
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1992
  • A Máa Bá Yín Lọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2020
  • Ta Ni Yóò “Yè Bọ́”?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
  • Orúkọ Ọlọ́run
    Jí!—2017
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 October ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓẸ́LÌ 1-3

‘Àwọn Ọmọkùnrin Yín àti Àwọn Ọmọbìnrin Yín Yóò Máa Sọ Tẹ́lẹ̀’

2:28, 29

Àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró ń kópa nínú iṣẹ́ ìsọtẹ́lẹ̀. Wọ́n ń sọ̀rọ̀ nípa “àwọn ohun ọlá ńlá Ọlọ́run” wọ́n sì ń kéde “ìhìn rere ìjọba” náà. (Iṣe 2:​11, 17-21; Mt 24:14) Àwọn àgùntàn mìíràn ń tì wọ́n lẹ́yìn lẹ́nu iṣẹ́ yìí

Nígbà Pẹ́ńtíkọ́sì, Kristẹni kan tó jẹ́ ẹni àmì òróró ń “sọ tẹ́lẹ̀” nípa wíwàásù “ìhìn rere ìjọba” náà fún àwọn èèyàn láti onírúurú ẹ̀yà

2:32

Kí ló túmọ̀ sí láti “ké pe orúkọ Jèhófà”?

  • Ká mọ orúkọ rẹ̀

  • Ká bọ̀wọ̀ fún orúkọ rẹ̀

  • Ká gbára lé Ẹni tó ń jẹ́ orúkọ náà ká sì gbẹ́kẹ̀ lé e

Bi ara rẹ pé, ‘Báwo ni mo ṣe lè ti àwọn ẹni àmì òróró lẹ́yìn lẹ́nu iṣẹ́ ìsọtẹ́lẹ̀?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́