ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp20 No. 3 ojú ìwé 16
  • Ṣé O Ti Béèrè Rí?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé O Ti Béèrè Rí?
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?
    Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?
  • Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?
    Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?
  • Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì?
    Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì?
  • Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀?
    Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀?
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
wp20 No. 3 ojú ìwé 16

Ṣé O Ti Béèrè Rí?

  • Fóònù kan wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kọ́ọ̀bù kọfí méjì. Ìwé náà Ìgbàgbọ́ Òdodo Ló Máa Mú Kó O Ní Ayọ̀ ni wọ́n gbé sójú fóònù náà.

    Kí ló dé tí ìṣòro fi pọ̀ gan-an láyé?

  • Báwo lo ṣe máa rí ọgbọ́n tó o lè fi kojú ìṣòro ìgbésí ayé?

  • Ṣé Ọlọ́run kà ẹ́ sí pàtàkì?​—1 Pétérù 5:​6, 7.

  • Báwo lo ṣe lè mọ̀ nípa Ọlọ́run àti ohun tó fẹ́?

Àìmọye èèyàn ti rí ìdáhùn tó tẹ́ wọn lọ́rùn sáwọn ìbéèrè yìí nígbà tí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ nínú Ìwé Mímọ́. Ìwọ náà lè ṣe bẹ́ẹ̀.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, jọ̀ọ́ sọ fún àwọn tó ṣe ìwé ìròyìn yìí pé kí wọ́n fún ẹ ní ìwé náà, Ìgbàgbọ́ Òdodo Ló Máa Mú Kó O Ní Ayọ̀. Ọ̀fẹ́ ni. O sì lè kà á lórí ìkànnì www.jw.org.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́