ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 3
  • Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Ẹ Kọ́ Wọn Láti Pa Gbogbo Ohun Tí Mo Ti Pa Láṣẹ Fún Yín Mọ́’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Láti Máa Pa Àṣẹ Kristi Mọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2020
  • Kọ́ Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Láti Máa Rìn Lọ́nà Tí Ọlọ́run Fẹ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2006
  • “Ẹ Lọ, Kí Ẹ sì Máa Sọ Àwọn Ènìyàn . . . Di Ọmọ Ẹ̀yìn”
    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 3
Jésù ní kí àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ sọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 27-28

Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn​—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo?

28:18-20

Kí Nìdí? Jèhófà fún Jésù ní ọlá àṣẹ tó gbòòrò gan-an

Níbo? Jésù pàṣẹ fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ pé kí wọ́n sọ “àwọn ènìyàn gbogbo orílẹ̀-èdè” di ọmọ ẹ̀yìn

A ó máa bá a lọ láti kọ́ àwọn èèyàn kí wọ́n lè máa pa gbogbo ohun tí Jésù ti pa láṣẹ fún wa mọ́

  • Wọ́n ń kọ́ ọkùnrin kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

    Báwo la ṣe ń kọ́ àwọn ẹlòmíì ní àṣẹ Jésù?

  • Wọ́n ń ran akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan lọ́wọ́ kó lè máa fàwọn ẹ̀kọ́ Jésù sílò

    Báwo la ṣe lè ran ẹni tí à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ láti fi ẹ̀kọ́ Jésù sílò?

  • Ó ń bá akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ṣiṣẹ́ lóde ẹ̀rí

    Báwo la ṣe lè ran ẹni tí à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́ láti máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́