ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 4
  • “A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìdí Tí Àwọn Èèyàn Fi Ń Ṣàìsàn
    Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà
  • “A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì Ọ́”
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
  • Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ṣé Ọlọ́run Máa Dárí Jì Mí?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 4
Jésù wà lórí ìtẹ́ rẹ̀ lọ́run

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 1-2

“A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì”

2:5-12

Wọ́n gba orí òrùlé gbé ọkùnrin kan tó yarọ wọlé síbi tí Jésù wà

Ẹ̀kọ́ wo ni a rí kọ́ nínú iṣẹ́ ìyanu yìí?

  • Ẹ̀ṣẹ̀ tá a jogún ló jẹ́ ká máa ṣàìsàn

  • Jésù ní agbára láti dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini àti láti mú àwọn aláìsàn lára dá

  • Nínú Ìjọba Ọlọ́run, Jésù máa mú àìpé àti àìsàn kúrò títí láé

Báwo ni Máàkù 2:5-12 ṣe lè ràn mí lọ́wọ́ láti fara dà á tí mo bá ń ṣàìsàn?

Ọkùnrin afọ́jú kan ríran; ọkùnrin arọ kan dìde látorí àga àwọn arọ
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́