ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 1-2
Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́ Tí Jésù Ṣe
Iṣẹ́ ìyanu àkọ́kọ́ tí Jésù ṣe jẹ́ ká mọ irú ẹni tó jẹ́. Kí ni ìtàn Bíbélì yìí kọ́ wa nípa àwọn nǹkan yìí?
Jésù ní èrò tó tọ́ nípa fàájì, ó gbádùn ara ẹ̀, ó sì lo àkókò tó tura pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀
Jésù máa ń bìkítà nípa bọ́rọ̀ ṣe rí lára àwọn ẹlòmíì
Ọ̀làwọ́ ni Jésù